Al-A'raf · 19/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-A'raf
وَيَا آدَمُ اسْكُنْ أَنتَ وَزَوْجُكَ الْجَنَّةَ فَكُلَا مِنْ حَيْثُ شِئْتُمَا وَلَا تَقْرَبَا هَٰذِهِ الشَّجَرَةَ فَتَكُونَا مِنَ الظَّالِمِينَ ١٩
Transliteration
Wa yaaa Aadamus kun anta wa zawjukal Jannata fakulaa min haisu shi`tumaa wa laa taqrabaa haazihish shajarata fatakoonaa minza zaalimeen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Adam, ki iwo ati iyawo re maa gbe ninu Ogba Idera. Nitori naa, e maa je nibikibi ti e ba fe. Ki e si ma se sunmo igi yii nitori ki e ma baa wa ninu awon alabosi
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 17-21 — Al-A'raf
17ثُمَّ لَآتِيَنَّهُم مِّن بَيْنِ أَيْدِيهِمْ وَمِنْ خَلْفِهِمْ وَعَنْ أَيْمَانِهِمْ وَعَن شَمَائِلِهِمْ ۖ وَلَا تَجِدُ أَكْثَرَهُمْ شَاكِرِينَ
Leyin naa, dajudaju emi yoo wa ba won lati iwaju won, lati eyin won, lati otun won ati osi won. Iwo ko si nii ri opolopo won ni oludupe (fun O)
18قَالَ اخْرُجْ مِنْهَا مَذْءُومًا مَّدْحُورًا ۖ لَّمَن تَبِعَكَ مِنْهُمْ لَأَمْلَأَنَّ جَهَنَّمَ مِنكُمْ أَجْمَعِينَ
(Allahu) so pe: "Jade kuro nibi (ki o si di) alabuku, eni-aledanu. Dajudaju enikeni t’o ba tele o ninu won, dajudaju Emi yoo fi gbogbo yin kun inu ina Jahanamo
19وَيَا آدَمُ اسْكُنْ أَنتَ وَزَوْجُكَ الْجَنَّةَ فَكُلَا مِنْ حَيْثُ شِئْتُمَا وَلَا تَقْرَبَا هَٰذِهِ الشَّجَرَةَ فَتَكُونَا مِنَ الظَّالِمِينَ
Adam, ki iwo ati iyawo re maa gbe ninu Ogba Idera. Nitori naa, e maa je nibikibi ti e ba fe. Ki e si ma se sunmo igi yii nitori ki e ma baa wa ninu awon alabosi
20فَوَسْوَسَ لَهُمَا الشَّيْطَانُ لِيُبْدِيَ لَهُمَا مَا وُورِيَ عَنْهُمَا مِن سَوْآتِهِمَا وَقَالَ مَا نَهَاكُمَا رَبُّكُمَا عَنْ هَٰذِهِ الشَّجَرَةِ إِلَّا أَن تَكُونَا مَلَكَيْنِ أَوْ تَكُونَا مِنَ الْخَالِدِينَ
Esu si ko royiroyi ba awon mejeeji nitori ki o le fi ohun ti A fi pamo ninu ihoho ara won han won. O si wi pe: "Oluwa eyin mejeeji ko ko igi yii fun yin bi ko se pe ki eyin mejeeji ma baa di molaika tabi ki eyin mejeeji ma baa di olusegbere
21وَقَاسَمَهُمَا إِنِّي لَكُمَا لَمِنَ النَّاصِحِينَ
O si bura fun awon mejeeji pe: "Dajudaju emi wa ninu awon onimoran fun eyin mejeeji
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
19Ẹsẹ
Itumọ — Al-A'raf 19
Surah Al-A'raf Ẹsẹ 19 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Adam, ki iwo ati iyawo re maa gbe ninu Ogba…Surah Ẹsẹ 19/206 — Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-A'raf Gbọ, Al-A'raf Itumọ, Al-A'raf mp3, Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 17–21. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








