Al-Baqarah · 148/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
وَلِكُلٍّ وِجْهَةٌ هُوَ مُوَلِّيهَا ۖ فَاسْتَبِقُوا الْخَيْرَاتِ ۚ أَيْنَ مَا تَكُونُوا يَأْتِ بِكُمُ اللَّهُ جَمِيعًا ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ ۝١٤٨
Wa likullinw wijhatun huwa muwalleehaa fastabiqul khairaat; ayna maa takoonoo yaati bikumullaahu jamee`aa; innal laaha `alaa kulli shai`in qadeer
📖 Ni Yorùbá
Ikookan (ijo elesin) l’o ni ibukojusi t’o n koju si. Nitori naa, e yara gbawaju nibi awon ise rere. Ibikibi ti e ba wa, Allahu yo mu gbogbo yin wa (ni Ojo Ajinde). Dajudaju Alagbara ni Allahu lori gbogbo nnkan
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 146-150 — Al-Baqarah

146الَّذِينَ آتَيْنَاهُمُ الْكِتَابَ يَعْرِفُونَهُ كَمَا يَعْرِفُونَ أَبْنَاءَهُمْ ۖ وَإِنَّ فَرِيقًا مِّنْهُمْ لَيَكْتُمُونَ الْحَقَّ وَهُمْ يَعْلَمُونَ
Awon ti A fun ni Tira, won mo Anabi (sollalahu alayhi wa sallam) gege bi won se mo awon omo won. Dajudaju awon ijo kan wa ninu won ti won kuku n fi ododo pamo; won si mo
147الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ ۖ فَلَا تَكُونَنَّ مِنَ الْمُمْتَرِينَ
Ododo naa wa lati odo Oluwa re. Nitori naa, o o gbodo wa lara awon oniyemeji
148وَلِكُلٍّ وِجْهَةٌ هُوَ مُوَلِّيهَا ۖ فَاسْتَبِقُوا الْخَيْرَاتِ ۚ أَيْنَ مَا تَكُونُوا يَأْتِ بِكُمُ اللَّهُ جَمِيعًا ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Ikookan (ijo elesin) l’o ni ibukojusi t’o n koju si. Nitori naa, e yara gbawaju nibi awon ise rere. Ibikibi ti e ba wa, Allahu yo mu gbogbo yin wa (ni Ojo Ajinde). Dajudaju Alagbara ni Allahu lori gbogbo nnkan
149وَمِنْ حَيْثُ خَرَجْتَ فَوَلِّ وَجْهَكَ شَطْرَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ ۖ وَإِنَّهُ لَلْحَقُّ مِن رَّبِّكَ ۗ وَمَا اللَّهُ بِغَافِلٍ عَمَّا تَعْمَلُونَ
Ibikibi ti o ba jade lo, koju re si agbegbe Mosalasi Haram, nitori pe dajudaju ododo ni lati odo Oluwa re. Allahu ko si nii gbagbe ohun ti e n se nise
150وَمِنْ حَيْثُ خَرَجْتَ فَوَلِّ وَجْهَكَ شَطْرَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ ۚ وَحَيْثُ مَا كُنتُمْ فَوَلُّوا وُجُوهَكُمْ شَطْرَهُ لِئَلَّا يَكُونَ لِلنَّاسِ عَلَيْكُمْ حُجَّةٌ إِلَّا الَّذِينَ ظَلَمُوا مِنْهُمْ فَلَا تَخْشَوْهُمْ وَاخْشَوْنِي وَلِأُتِمَّ نِعْمَتِي عَلَيْكُمْ وَلَعَلَّكُمْ تَهْتَدُونَ
Ibikibi ti o ba jade lo, koju re si agbegbe Mosalasi Haram. Ati pe ibikibi ti e ba wa, e koju yin si agbegbe re, nitori ki awon eniyan ma baa ni awijare lori yin, ayafi awon ti won sabosi ninu won (ti won ko ye ja yin niyan). Nitori naa, e ma se paya won. E paya Mi, nitori ki Ng le pe idera Mi fun yin ati nitori ki e le mona ooji re maa wa ni egbe otun re nikete ti oorun ba yetari. Nigba ti opin eba oke ila oorun n je ariwa-ila oorun (north-east) opin eba isale ila oorun si n je gusu-ila oorun (south-east). Nitori naa
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
148Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 148

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 148 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ikookan (ijo elesin) l’o ni ibukojusi t’o n koju si.…

Surah Ẹsẹ 148/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 146–150. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers