Al-Baqarah · 159/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
إِنَّ الَّذِينَ يَكْتُمُونَ مَا أَنزَلْنَا مِنَ الْبَيِّنَاتِ وَالْهُدَىٰ مِن بَعْدِ مَا بَيَّنَّاهُ لِلنَّاسِ فِي الْكِتَابِ ۙ أُولَٰئِكَ يَلْعَنُهُمُ اللَّهُ وَيَلْعَنُهُمُ اللَّاعِنُونَ ۝١٥٩
Innal lazeena yaktumoona maaa anzalnaa minal baiyinaati walhudaa mim ba`di maa baiyannaahu linnaasi fil kitaabi ulaaa`ika yal`anuhumul laahu wa yal`anuhumul laa `inoon
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon t’o n daso bo ohun ti A sokale ninu awon eri t’o yanju ati imona, leyin ti A ti se alaye re fun awon eniyan sinu Tira, awon wonyen ni Allahu n sebi le. Awon olusebi si n sebi le won
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 157-161 — Al-Baqarah

157أُولَٰئِكَ عَلَيْهِمْ صَلَوَاتٌ مِّن رَّبِّهِمْ وَرَحْمَةٌ ۖ وَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُهْتَدُونَ
Awon wonyen ni aforijin ati ike yo maa be fun lati odo Oluwa won. Awon wonyen, awon si ni olumona
158۞ إِنَّ الصَّفَا وَالْمَرْوَةَ مِن شَعَائِرِ اللَّهِ ۖ فَمَنْ حَجَّ الْبَيْتَ أَوِ اعْتَمَرَ فَلَا جُنَاحَ عَلَيْهِ أَن يَطَّوَّفَ بِهِمَا ۚ وَمَن تَطَوَّعَ خَيْرًا فَإِنَّ اللَّهَ شَاكِرٌ عَلِيمٌ
Dajudaju (apata) Sofa ati (apata) Morwah wa ninu awon arisami fun esin Allahu. Nitori naa, enikeni ti o ba se ise Hajj si Ile naa tabi o se ise ‘Umrah, ko si ese fun un lati rin yika (laaarin apata) mejeeji. Enikeni ti o ba si finnu-findo se ise asegbore, dajudaju Allahu ni Amoore, Onimo
159إِنَّ الَّذِينَ يَكْتُمُونَ مَا أَنزَلْنَا مِنَ الْبَيِّنَاتِ وَالْهُدَىٰ مِن بَعْدِ مَا بَيَّنَّاهُ لِلنَّاسِ فِي الْكِتَابِ ۙ أُولَٰئِكَ يَلْعَنُهُمُ اللَّهُ وَيَلْعَنُهُمُ اللَّاعِنُونَ
Dajudaju awon t’o n daso bo ohun ti A sokale ninu awon eri t’o yanju ati imona, leyin ti A ti se alaye re fun awon eniyan sinu Tira, awon wonyen ni Allahu n sebi le. Awon olusebi si n sebi le won
160إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا وَأَصْلَحُوا وَبَيَّنُوا فَأُولَٰئِكَ أَتُوبُ عَلَيْهِمْ ۚ وَأَنَا التَّوَّابُ الرَّحِيمُ
Ayafi awon t’o ronu piwada, ti won se atunse, ti won si safi han ododo, nitori naa awon wonyen ni Mo maa gba ironupiwada won. Emi si ni Olugba-ironupiwada, Asake-orun
161إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا وَمَاتُوا وَهُمْ كُفَّارٌ أُولَٰئِكَ عَلَيْهِمْ لَعْنَةُ اللَّهِ وَالْمَلَائِكَةِ وَالنَّاسِ أَجْمَعِينَ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si ku nigba ti won je alaigbagbo, awon wonyen ni egun Allahu, (egun) awon molaika ati (egun) eniyan patapata n be lori won
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
159Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 159

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 159 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon t’o n daso bo ohun ti A sokale…

Surah Ẹsẹ 159/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 157–161. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers