Al-Anbiya · 29/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Anbiya
۞ وَمَن يَقُلْ مِنْهُمْ إِنِّي إِلَٰهٌ مِّن دُونِهِ فَذَٰلِكَ نَجْزِيهِ جَهَنَّمَ ۚ كَذَٰلِكَ نَجْزِي الظَّالِمِينَ ۝٢٩
Wa mai yaqul minhum inneee ilaahum min doonihee fazaalika najzeehi Jahannam; kazaalika najziz zaalimeen
📖 Ni Yorùbá
Ati pe enikeni ninu won ti o ba wi pe: “Dajudaju emi ni olohun leyin Re.” Nitori iyen si ni A oo fi san an ni esan ina Jahanamo. Bayen si ni A se n san awon alabosi ni esan

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 27-31 — Surah Al-Anbiya

27لَا يَسْبِقُونَهُ بِالْقَوْلِ وَهُم بِأَمْرِهِ يَعْمَلُونَ
Won ki i siwaju Allahu soro. Won si n sise pelu ase Re
28يَعْلَمُ مَا بَيْنَ أَيْدِيهِمْ وَمَا خَلْفَهُمْ وَلَا يَشْفَعُونَ إِلَّا لِمَنِ ارْتَضَىٰ وَهُم مِّنْ خَشْيَتِهِ مُشْفِقُونَ
(Allahu) mo ohun t’o n be niwaju won ati ohun t’o n be leyin won. Won ko si nii sipe (eni kan) afi eni ti (Allahu) ba yonu si. Won tun n paya fun iberu Re
29۞ وَمَن يَقُلْ مِنْهُمْ إِنِّي إِلَٰهٌ مِّن دُونِهِ فَذَٰلِكَ نَجْزِيهِ جَهَنَّمَ ۚ كَذَٰلِكَ نَجْزِي الظَّالِمِينَ
Ati pe enikeni ninu won ti o ba wi pe: “Dajudaju emi ni olohun leyin Re.” Nitori iyen si ni A oo fi san an ni esan ina Jahanamo. Bayen si ni A se n san awon alabosi ni esan
30أَوَلَمْ يَرَ الَّذِينَ كَفَرُوا أَنَّ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضَ كَانَتَا رَتْقًا فَفَتَقْنَاهُمَا ۖ وَجَعَلْنَا مِنَ الْمَاءِ كُلَّ شَيْءٍ حَيٍّ ۖ أَفَلَا يُؤْمِنُونَ
Se awon t’o sai gbagbo ko ri i pe dajudaju awon sanmo le po ati ile naa le po tele ni, A si ya won si otooto, A si se gbogbo nnkan ni abemi lati inu omi? Nitori naa, se won ko nii gbagbo ni? lile-papo” itumo “fatƙ” si ni “ela
31وَجَعَلْنَا فِي الْأَرْضِ رَوَاسِيَ أَن تَمِيدَ بِهِمْ وَجَعَلْنَا فِيهَا فِجَاجًا سُبُلًا لَّعَلَّهُمْ يَهْتَدُونَ
A si fi awon apata t’o duro gbagidi sinu ile ki o ma fi le mi mo won lese. A si fi awon ona fife saaarin awon apata nitori ki won le ri ona to
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
29Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 29

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 29 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe enikeni ninu won ti o ba wi pe:…

Surah Ẹsẹ 29/112 — Surah Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Anbiya Gbọ, Surah Al-Anbiya Itumọ, Surah Al-Anbiya mp3, Surah Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 27–31. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers