An-Naml · 84/93
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Naml
حَتَّىٰ إِذَا جَاءُوا قَالَ أَكَذَّبْتُم بِآيَاتِي وَلَمْ تُحِيطُوا بِهَا عِلْمًا أَمَّاذَا كُنتُمْ تَعْمَلُونَ ۝٨٤
Hattaaa izaa jaaa`oo qaala akazzabtum bi Aayaatee wa lam tuheetoo bihaa `ilman ammaazaa kuntum ta`maloon
📖 Ni Yorùbá
Titi (di) igba ti won ba de (tan), (Allahu) yoo so pe: "Se e pe awon ayah Mi niro, ti eyin ko si ni imo kan nipa re (ti e le fi ja a niro)? Tabi ki ni e n se nise (nile aye)
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 82-86 — An-Naml

82۞ وَإِذَا وَقَعَ الْقَوْلُ عَلَيْهِمْ أَخْرَجْنَا لَهُمْ دَابَّةً مِّنَ الْأَرْضِ تُكَلِّمُهُمْ أَنَّ النَّاسَ كَانُوا بِآيَاتِنَا لَا يُوقِنُونَ
Nigba ti oro naa ba ko le won lori, A maa mu eranko kan jade fun won lati inu ile, ti o maa ba won soro pe: “Dajudaju awon eniyan ki i nimo amodaju nipa awon ayah Wa.”
83وَيَوْمَ نَحْشُرُ مِن كُلِّ أُمَّةٍ فَوْجًا مِّمَّن يُكَذِّبُ بِآيَاتِنَا فَهُمْ يُوزَعُونَ
Ati pe (ranti) ojo ti A oo ko ijo kan jo ninu ijo kookan ninu awon t’o n pe awon ayah Wa niro. A o si ko won jo papo mora won
84حَتَّىٰ إِذَا جَاءُوا قَالَ أَكَذَّبْتُم بِآيَاتِي وَلَمْ تُحِيطُوا بِهَا عِلْمًا أَمَّاذَا كُنتُمْ تَعْمَلُونَ
Titi (di) igba ti won ba de (tan), (Allahu) yoo so pe: "Se e pe awon ayah Mi niro, ti eyin ko si ni imo kan nipa re (ti e le fi ja a niro)? Tabi ki ni e n se nise (nile aye)
85وَوَقَعَ الْقَوْلُ عَلَيْهِم بِمَا ظَلَمُوا فَهُمْ لَا يَنطِقُونَ
Oro naa si ko le won lori nitori pe won sabosi. Won ko si nii soro
86أَلَمْ يَرَوْا أَنَّا جَعَلْنَا اللَّيْلَ لِيَسْكُنُوا فِيهِ وَالنَّهَارَ مُبْصِرًا ۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَآيَاتٍ لِّقَوْمٍ يُؤْمِنُونَ
Se won ko ri i pe dajudaju Awa l’A da oru nitori ki won le sinmi ninu re, (A si da) osan (nitori ki won le) riran? Dajudaju ami wa ninu iyen fun ijo onigbagbo ododo
An-NamlAtokọ Kurani
93Ẹsẹ
MeccanRevelation
84Ẹsẹ

Itumọ — An-Naml 84

Surah An-Naml Ẹsẹ 84 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Titi (di) igba ti won ba de (tan), (Allahu) yoo…

Surah Ẹsẹ 84/93 — An-Naml النمل (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Naml Gbọ, An-Naml Itumọ, An-Naml mp3, An-Naml pdf. Ẹsẹ 82–86. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers