Aal-Imran · 33/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
۞ إِنَّ اللَّهَ اصْطَفَىٰ آدَمَ وَنُوحًا وَآلَ إِبْرَاهِيمَ وَآلَ عِمْرَانَ عَلَى الْعَالَمِينَ ۝٣٣
Innal laahas tafaaa Aadama wa Noohanw wa Aala Ibraaheema wa Aala Imraana `alal `aalameen
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju Allahu sa Adam, Nuh, ara ile ’Ibrohim ati ara ile ‘Imron lesa lori awon eda (asiko tiwon)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 31-35 — Surah Aal-Imran

31قُلْ إِن كُنتُمْ تُحِبُّونَ اللَّهَ فَاتَّبِعُونِي يُحْبِبْكُمُ اللَّهُ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ذُنُوبَكُمْ ۗ وَاللَّهُ غَفُورٌ رَّحِيمٌ
So pe: “Ti eyin ba nifee Allahu, e tele mi, Allahu maa nifee yin, O si maa fori ese yin jin yin. Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
32قُلْ أَطِيعُوا اللَّهَ وَالرَّسُولَ ۖ فَإِن تَوَلَّوْا فَإِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ الْكَافِرِينَ
So pe: “E tele (ti) Allahu ati Ojise. Ti e ba si peyin da, dajudaju Allahu ko nifee awon alaigbagbo
33۞ إِنَّ اللَّهَ اصْطَفَىٰ آدَمَ وَنُوحًا وَآلَ إِبْرَاهِيمَ وَآلَ عِمْرَانَ عَلَى الْعَالَمِينَ
Dajudaju Allahu sa Adam, Nuh, ara ile ’Ibrohim ati ara ile ‘Imron lesa lori awon eda (asiko tiwon)
34ذُرِّيَّةً بَعْضُهَا مِن بَعْضٍ ۗ وَاللَّهُ سَمِيعٌ عَلِيمٌ
Won je aromodomo; apa kan won wa lati ara apa kan. Allahu si ni Olugbo, Onimo
35إِذْ قَالَتِ امْرَأَتُ عِمْرَانَ رَبِّ إِنِّي نَذَرْتُ لَكَ مَا فِي بَطْنِي مُحَرَّرًا فَتَقَبَّلْ مِنِّي ۖ إِنَّكَ أَنتَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
(E ranti) nigba ti aya ‘Imron so pe: "Oluwa mi, dajudaju emi fi ohun ti n be ninu mi jejee fun O (pe) mo maa ya a soto (fun esin Re). Nitori naa, gba a lowo mi, dajudaju Iwo ni Olugbo, Onimo
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
33Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 33

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 33 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju Allahu sa Adam, Nuh, ara ile ’Ibrohim ati ara…

Surah Ẹsẹ 33/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 31–35. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers