Aal-Imran · 36/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
فَلَمَّا وَضَعَتْهَا قَالَتْ رَبِّ إِنِّي وَضَعْتُهَا أُنثَىٰ وَاللَّهُ أَعْلَمُ بِمَا وَضَعَتْ وَلَيْسَ الذَّكَرُ كَالْأُنثَىٰ ۖ وَإِنِّي سَمَّيْتُهَا مَرْيَمَ وَإِنِّي أُعِيذُهَا بِكَ وَذُرِّيَّتَهَا مِنَ الشَّيْطَانِ الرَّجِيمِ ۝٣٦
Falammaa waqa`athaa qaalat Rabbi innee wada`tuhaaa unsaa wallaahu a`lamu bimaa wada`at wa laisaz zakaru kalunsaa wa innee sammaituhaa Maryama wa innee u`eezuhaa bika wa zurriyyatahaa minash Shaitaanir Rajeem
📖 Ni Yorùbá
Nigba ti o bi i, o so pe: “Oluwa mi, dajudaju mo bi i ni obinrin - Allahu si nimo julo nipa ohun ti o bi – okunrin ko si da bi obinrin. Dajudaju emi so o ni Moryam. Ati pe dajudaju mo n fi O wa aabo fun oun ati aromodomo re lodo Esu, eni eko.”
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 34-38 — Aal-Imran

34ذُرِّيَّةً بَعْضُهَا مِن بَعْضٍ ۗ وَاللَّهُ سَمِيعٌ عَلِيمٌ
Won je aromodomo; apa kan won wa lati ara apa kan. Allahu si ni Olugbo, Onimo
35إِذْ قَالَتِ امْرَأَتُ عِمْرَانَ رَبِّ إِنِّي نَذَرْتُ لَكَ مَا فِي بَطْنِي مُحَرَّرًا فَتَقَبَّلْ مِنِّي ۖ إِنَّكَ أَنتَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
(E ranti) nigba ti aya ‘Imron so pe: "Oluwa mi, dajudaju emi fi ohun ti n be ninu mi jejee fun O (pe) mo maa ya a soto (fun esin Re). Nitori naa, gba a lowo mi, dajudaju Iwo ni Olugbo, Onimo
36فَلَمَّا وَضَعَتْهَا قَالَتْ رَبِّ إِنِّي وَضَعْتُهَا أُنثَىٰ وَاللَّهُ أَعْلَمُ بِمَا وَضَعَتْ وَلَيْسَ الذَّكَرُ كَالْأُنثَىٰ ۖ وَإِنِّي سَمَّيْتُهَا مَرْيَمَ وَإِنِّي أُعِيذُهَا بِكَ وَذُرِّيَّتَهَا مِنَ الشَّيْطَانِ الرَّجِيمِ
Nigba ti o bi i, o so pe: “Oluwa mi, dajudaju mo bi i ni obinrin - Allahu si nimo julo nipa ohun ti o bi – okunrin ko si da bi obinrin. Dajudaju emi so o ni Moryam. Ati pe dajudaju mo n fi O wa aabo fun oun ati aromodomo re lodo Esu, eni eko.”
37فَتَقَبَّلَهَا رَبُّهَا بِقَبُولٍ حَسَنٍ وَأَنبَتَهَا نَبَاتًا حَسَنًا وَكَفَّلَهَا زَكَرِيَّا ۖ كُلَّمَا دَخَلَ عَلَيْهَا زَكَرِيَّا الْمِحْرَابَ وَجَدَ عِندَهَا رِزْقًا ۖ قَالَ يَا مَرْيَمُ أَنَّىٰ لَكِ هَٰذَا ۖ قَالَتْ هُوَ مِنْ عِندِ اللَّهِ ۖ إِنَّ اللَّهَ يَرْزُقُ مَن يَشَاءُ بِغَيْرِ حِسَابٍ
Oluwa re si gba adua naa ni gbigba daadaa. O si mu omo naa dagba ni idagba daadaa. O si fi Zakariyya se alagbato re. Igbakigba ti Zakariyya ba wole to o ninu ile ijosin, o maa ba ese (eso) lodo re. (Zakariyya a) so pe: “Moryam, bawo ni eyi se je tire?” (Moryam a) so pe: "O wa lati odo Allahu. Dajudaju Allahu n se arisiki fun eni ti O ba fe ni opolopo
38هُنَالِكَ دَعَا زَكَرِيَّا رَبَّهُ ۖ قَالَ رَبِّ هَبْ لِي مِن لَّدُنكَ ذُرِّيَّةً طَيِّبَةً ۖ إِنَّكَ سَمِيعُ الدُّعَاءِ
Ibeyen ni Zakariyya ti pe Oluwa re. O so pe: "Oluwa mi, ta mi ni ore aromodomo daadaa lati odo Re. Dajudaju Iwo ni Olugbo adua
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
36Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 36

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 36 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nigba ti o bi i, o so pe: “Oluwa mi,…

Surah Ẹsẹ 36/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 34–38. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers