Aal-Imran · 68/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
إِنَّ أَوْلَى النَّاسِ بِإِبْرَاهِيمَ لَلَّذِينَ اتَّبَعُوهُ وَهَٰذَا النَّبِيُّ وَالَّذِينَ آمَنُوا ۗ وَاللَّهُ وَلِيُّ الْمُؤْمِنِينَ ۝٦٨
Innaa awlan naasi bi Ibraaheema lallazeenat taba `oohu wa haazan nabiyyu wallazeena aamanoo; wallaahu waliyyul mu`mineen
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju awon eniyan t’o sunmo (Anabi) ’Ibrohim julo ni awon t’o tele e ati Anabi yii (Anabi Muhammad s.a.w.) ati awon t’o gbagbo ni ododo. Allahu ni Alatileyin fun awon onigbagbo ododo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 66-70 — Surah Aal-Imran

66هَا أَنتُمْ هَٰؤُلَاءِ حَاجَجْتُمْ فِيمَا لَكُم بِهِ عِلْمٌ فَلِمَ تُحَاجُّونَ فِيمَا لَيْسَ لَكُم بِهِ عِلْمٌ ۚ وَاللَّهُ يَعْلَمُ وَأَنتُمْ لَا تَعْلَمُونَ
Eyin ni iwonyi ti e n jiyan nipa ohun ti e nimo nipa re! Ki ni o tun n mu yin jiyan nipa ohun ti e o nimo nipa re? Allahu nimo. Eyin ko si nimo
67مَا كَانَ إِبْرَاهِيمُ يَهُودِيًّا وَلَا نَصْرَانِيًّا وَلَٰكِن كَانَ حَنِيفًا مُّسْلِمًا وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
(Anabi) ’Ibrohim ki i se yehudi, ki i se kristieni, sugbon o je oluduro-deede, musulumi. Ko si si ninu awon osebo
68إِنَّ أَوْلَى النَّاسِ بِإِبْرَاهِيمَ لَلَّذِينَ اتَّبَعُوهُ وَهَٰذَا النَّبِيُّ وَالَّذِينَ آمَنُوا ۗ وَاللَّهُ وَلِيُّ الْمُؤْمِنِينَ
Dajudaju awon eniyan t’o sunmo (Anabi) ’Ibrohim julo ni awon t’o tele e ati Anabi yii (Anabi Muhammad s.a.w.) ati awon t’o gbagbo ni ododo. Allahu ni Alatileyin fun awon onigbagbo ododo
69وَدَّت طَّائِفَةٌ مِّنْ أَهْلِ الْكِتَابِ لَوْ يُضِلُّونَكُمْ وَمَا يُضِلُّونَ إِلَّا أَنفُسَهُمْ وَمَا يَشْعُرُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab fe lati si yin lona. Won ko le si enikeni lona afi ara won, won ko si fura
70يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَأَنتُمْ تَشْهَدُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, e si n jerii (si ododo re)
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
68Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 68

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 68 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju awon eniyan t’o sunmo (Anabi) ’Ibrohim julo ni awon…

Surah Ẹsẹ 68/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 66–70. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers