Az-Zumar · 56/75
Itumọ Aṣẹ ohun — Az-Zumar
أَن تَقُولَ نَفْسٌ يَا حَسْرَتَا عَلَىٰ مَا فَرَّطتُ فِي جَنبِ اللَّهِ وَإِن كُنتُ لَمِنَ السَّاخِرِينَ ۝٥٦
An taqoola nafsuny yaahasrataa `alaa maa farrattu fee jambil laahi wa in kuntu laminas saakhireen
📖 Ni Yorùbá
Nitori ki emi kan ma baa wi pe: "Mo ka abamo lori bi mo se jafara lori aitele ase Allahu. Ati pe emi wa ninu awon t’o n fi (oro Re) se yeye
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 54-58 — Az-Zumar

54وَأَنِيبُوا إِلَىٰ رَبِّكُمْ وَأَسْلِمُوا لَهُ مِن قَبْلِ أَن يَأْتِيَكُمُ الْعَذَابُ ثُمَّ لَا تُنصَرُونَ
E seri pada (ni ti ironupiwada) si odo Oluwa yin. Ki e si juwo-juse sile fun Un siwaju ki iya naa t’o wa ba yin. (Bi bee ko) leyin naa, A o nii ran yin lowo
55وَاتَّبِعُوا أَحْسَنَ مَا أُنزِلَ إِلَيْكُم مِّن رَّبِّكُم مِّن قَبْلِ أَن يَأْتِيَكُمُ الْعَذَابُ بَغْتَةً وَأَنتُمْ لَا تَشْعُرُونَ
Ki e si tele ohun ti o dara julo ti won sokale fun yin lati odo Oluwa yin siwaju ki iya naa to wa ba yin ni ojiji, nigba ti eyin ko nii fura
56أَن تَقُولَ نَفْسٌ يَا حَسْرَتَا عَلَىٰ مَا فَرَّطتُ فِي جَنبِ اللَّهِ وَإِن كُنتُ لَمِنَ السَّاخِرِينَ
Nitori ki emi kan ma baa wi pe: "Mo ka abamo lori bi mo se jafara lori aitele ase Allahu. Ati pe emi wa ninu awon t’o n fi (oro Re) se yeye
57أَوْ تَقُولَ لَوْ أَنَّ اللَّهَ هَدَانِي لَكُنتُ مِنَ الْمُتَّقِينَ
Tabi ki o ma baa wi pe: "Ti o ba je pe Allahu fi ona mo mi ni, dajudaju emi iba wa ninu awon oluberu (Allahu)
58أَوْ تَقُولَ حِينَ تَرَى الْعَذَابَ لَوْ أَنَّ لِي كَرَّةً فَأَكُونَ مِنَ الْمُحْسِنِينَ
Tabi nigba ti o ba ri Ina ki o ma baa wi pe: "Ti o ba je pe ipadasaye wa fun mi ni, emi iba si wa ninu awon oluse-rere
Az-ZumarAtokọ Kurani
75Ẹsẹ
MeccanRevelation
56Ẹsẹ

Itumọ — Az-Zumar 56

Surah Az-Zumar Ẹsẹ 56 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nitori ki emi kan ma baa wi pe: "Mo ka…

Surah Ẹsẹ 56/75 — Az-Zumar الزمر (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Az-Zumar Gbọ, Az-Zumar Itumọ, Az-Zumar mp3, Az-Zumar pdf. Ẹsẹ 54–58. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers