Al-Fath · 19/29
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Fath
وَمَغَانِمَ كَثِيرَةً يَأْخُذُونَهَا ۗ وَكَانَ اللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمًا ۝١٩
Wa maghaanima kaseera tany yaakhuzoonahaa; wa kaanal laahu `Azeezan Hakeemaa
📖 Ni Yorùbá
ati awon oro ogun opolopo ti won yoo ri ko. Allahu n je Alagbara, Ologbon
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 17-21 — Al-Fath

17لَّيْسَ عَلَى الْأَعْمَىٰ حَرَجٌ وَلَا عَلَى الْأَعْرَجِ حَرَجٌ وَلَا عَلَى الْمَرِيضِ حَرَجٌ ۗ وَمَن يُطِعِ اللَّهَ وَرَسُولَهُ يُدْخِلْهُ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ ۖ وَمَن يَتَوَلَّ يُعَذِّبْهُ عَذَابًا أَلِيمًا
Ko si ese fun afoju, ko si ese fun aro, ko si si ese fun alaisan (ti won ko ba lo soju ogun). Enikeni ti o ba tele ti Allahu ati Ojise Re, (Allahu) yoo mu un wo inu awon Ogba Idera, eyi ti awon odo n san ni isale re. Enikeni ti o ba si gbunri, O maa je e ni iya eleta-elero
18۞ لَّقَدْ رَضِيَ اللَّهُ عَنِ الْمُؤْمِنِينَ إِذْ يُبَايِعُونَكَ تَحْتَ الشَّجَرَةِ فَعَلِمَ مَا فِي قُلُوبِهِمْ فَأَنزَلَ السَّكِينَةَ عَلَيْهِمْ وَأَثَابَهُمْ فَتْحًا قَرِيبًا
Dajudaju Allahu ti yonu si awon onigbagbo ododo nigba ti won n sadehun fun o labe igi (pe awon ko nii fese fee loju ogun). Nitori naa, (Allahu) mo ohun ti o wa ninu okan won. O si so ifokanbale kale fun won. O si san won ni esan isegun t’o sunmo
19وَمَغَانِمَ كَثِيرَةً يَأْخُذُونَهَا ۗ وَكَانَ اللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمًا
ati awon oro ogun opolopo ti won yoo ri ko. Allahu n je Alagbara, Ologbon
20وَعَدَكُمُ اللَّهُ مَغَانِمَ كَثِيرَةً تَأْخُذُونَهَا فَعَجَّلَ لَكُمْ هَٰذِهِ وَكَفَّ أَيْدِيَ النَّاسِ عَنكُمْ وَلِتَكُونَ آيَةً لِّلْمُؤْمِنِينَ وَيَهْدِيَكُمْ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا
Ati pe Allahu sadehun awon oro ogun opolopo ti eyin yoo ri ko fun yin. O si tete mu eyi wa fun yin. O tun ko awon eniyan lowo ro fun yin nitori ki o le je ami kan fun awon onigbagbo ododo ati nitori ki O le fi ese yin rinle soju ona taara (’Islam)
21وَأُخْرَىٰ لَمْ تَقْدِرُوا عَلَيْهَا قَدْ أَحَاطَ اللَّهُ بِهَا ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرًا
Ati omiran ti e o lagbara lori re, (amo ti) Allahu ti rokirika re. Allahu si n je Alagbara lori gbogbo nnkan
Al-FathAtokọ Kurani
29Ẹsẹ
MedinanRevelation
19Ẹsẹ

Itumọ — Al-Fath 19

Surah Al-Fath Ẹsẹ 19 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : ati awon oro ogun opolopo ti won yoo ri ko.…

Surah Ẹsẹ 19/29 — Al-Fath الفتح (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Fath Gbọ, Al-Fath Itumọ, Al-Fath mp3, Al-Fath pdf. Ẹsẹ 17–21. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers