Al-Fath · 20/29
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Fath
وَعَدَكُمُ اللَّهُ مَغَانِمَ كَثِيرَةً تَأْخُذُونَهَا فَعَجَّلَ لَكُمْ هَٰذِهِ وَكَفَّ أَيْدِيَ النَّاسِ عَنكُمْ وَلِتَكُونَ آيَةً لِّلْمُؤْمِنِينَ وَيَهْدِيَكُمْ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا ۝٢٠
Wa`adakumul laahu ma ghaanima kaseeratan taakhuzoo nahaa fa`ajjala lakum haazihee wa kaffa aydiyan naasi `ankum wa litakoona aayatal lilmu`mineena wa yahdiyakum siraatam mustaqeema
📖 Ni Yorùbá
Ati pe Allahu sadehun awon oro ogun opolopo ti eyin yoo ri ko fun yin. O si tete mu eyi wa fun yin. O tun ko awon eniyan lowo ro fun yin nitori ki o le je ami kan fun awon onigbagbo ododo ati nitori ki O le fi ese yin rinle soju ona taara (’Islam)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 18-22 — Surah Al-Fath

18۞ لَّقَدْ رَضِيَ اللَّهُ عَنِ الْمُؤْمِنِينَ إِذْ يُبَايِعُونَكَ تَحْتَ الشَّجَرَةِ فَعَلِمَ مَا فِي قُلُوبِهِمْ فَأَنزَلَ السَّكِينَةَ عَلَيْهِمْ وَأَثَابَهُمْ فَتْحًا قَرِيبًا
Dajudaju Allahu ti yonu si awon onigbagbo ododo nigba ti won n sadehun fun o labe igi (pe awon ko nii fese fee loju ogun). Nitori naa, (Allahu) mo ohun ti o wa ninu okan won. O si so ifokanbale kale fun won. O si san won ni esan isegun t’o sunmo
19وَمَغَانِمَ كَثِيرَةً يَأْخُذُونَهَا ۗ وَكَانَ اللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمًا
ati awon oro ogun opolopo ti won yoo ri ko. Allahu n je Alagbara, Ologbon
20وَعَدَكُمُ اللَّهُ مَغَانِمَ كَثِيرَةً تَأْخُذُونَهَا فَعَجَّلَ لَكُمْ هَٰذِهِ وَكَفَّ أَيْدِيَ النَّاسِ عَنكُمْ وَلِتَكُونَ آيَةً لِّلْمُؤْمِنِينَ وَيَهْدِيَكُمْ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا
Ati pe Allahu sadehun awon oro ogun opolopo ti eyin yoo ri ko fun yin. O si tete mu eyi wa fun yin. O tun ko awon eniyan lowo ro fun yin nitori ki o le je ami kan fun awon onigbagbo ododo ati nitori ki O le fi ese yin rinle soju ona taara (’Islam)
21وَأُخْرَىٰ لَمْ تَقْدِرُوا عَلَيْهَا قَدْ أَحَاطَ اللَّهُ بِهَا ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرًا
Ati omiran ti e o lagbara lori re, (amo ti) Allahu ti rokirika re. Allahu si n je Alagbara lori gbogbo nnkan
22وَلَوْ قَاتَلَكُمُ الَّذِينَ كَفَرُوا لَوَلَّوُا الْأَدْبَارَ ثُمَّ لَا يَجِدُونَ وَلِيًّا وَلَا نَصِيرًا
Ti o ba je pe awon t’o sai gbagbo gbogun dide si yin ni, won iba peyin da (lati sagun fun yin). Leyin naa, won ko nii ri alaabo tabi alaranse kan
Al-FathAtokọ Kurani
29Ẹsẹ
MedinanRevelation
20Ẹsẹ

Itumọ — Al-Fath 20

Surah Al-Fath Ẹsẹ 20 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe Allahu sadehun awon oro ogun opolopo ti eyin…

Surah Ẹsẹ 20/29 — Surah Al-Fath الفتح (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Fath Gbọ, Surah Al-Fath Itumọ, Surah Al-Fath mp3, Surah Al-Fath pdf. Ẹsẹ 18–22. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers