Al-Qamar · 27/55
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qamar
إِنَّا مُرْسِلُو النَّاقَةِ فِتْنَةً لَّهُمْ فَارْتَقِبْهُمْ وَاصْطَبِرْ ۝٢٧
Innaa mursilun naaqati fitnatal lahum fartaqibhum wastabir
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju Awa maa ran abo rakunmi si won; (o maa je) adanwo fun won. Nitori naa, maa wo won niran na, ki o si se suuru

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 25-29 — Surah Al-Qamar

25أَأُلْقِيَ الذِّكْرُ عَلَيْهِ مِن بَيْنِنَا بَلْ هُوَ كَذَّابٌ أَشِرٌ
Se oun ni won so iranti kale fun laaarin wa? Rara o, opuro onigbeeraga ni
26سَيَعْلَمُونَ غَدًا مَّنِ الْكَذَّابُ الْأَشِرُ
Ni ola ni won yoo mo ta ni opuro onigbeeraga
27إِنَّا مُرْسِلُو النَّاقَةِ فِتْنَةً لَّهُمْ فَارْتَقِبْهُمْ وَاصْطَبِرْ
Dajudaju Awa maa ran abo rakunmi si won; (o maa je) adanwo fun won. Nitori naa, maa wo won niran na, ki o si se suuru
28وَنَبِّئْهُمْ أَنَّ الْمَاءَ قِسْمَةٌ بَيْنَهُمْ ۖ كُلُّ شِرْبٍ مُّحْتَضَرٌ
Ki o si fun won ni iro pe dajudaju pipin ni omi laaarin won. Gbogbo ipin omi si wa fun eni ti o ba kan lati wa si odo
29فَنَادَوْا صَاحِبَهُمْ فَتَعَاطَىٰ فَعَقَرَ
Nigba naa ni won pe eni won. O wa ona lati mu (rakunmi naa mole). O si pa a
Al-QamarAtokọ Kurani
55Ẹsẹ
MeccanRevelation
27Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qamar 27

Surah Al-Qamar Ẹsẹ 27 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju Awa maa ran abo rakunmi si won; (o maa…

Surah Ẹsẹ 27/55 — Surah Al-Qamar القمر (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qamar Gbọ, Surah Al-Qamar Itumọ, Surah Al-Qamar mp3, Surah Al-Qamar pdf. Ẹsẹ 25–29. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers