Ar-Rahman · 11/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
فِيهَا فَاكِهَةٌ وَالنَّخْلُ ذَاتُ الْأَكْمَامِ ۝١١
Feehaa faakihatunw wan nakhlu zaatul akmaam
📖 Ni Yorùbá
Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 9-13 — Surah Ar-Rahman

9وَأَقِيمُوا الْوَزْنَ بِالْقِسْطِ وَلَا تُخْسِرُوا الْمِيزَانَ
E gbe osuwon naa duro pelu dogbadogba. Ki e si ma se din osuwon ku
10وَالْأَرْضَ وَضَعَهَا لِلْأَنَامِ
Ile, (Allahu) te e sile fun awon eda
11فِيهَا فَاكِهَةٌ وَالنَّخْلُ ذَاتُ الْأَكْمَامِ
Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)
12وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
13فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
11Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 11

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 11 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)

Surah Ẹsẹ 11/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 9–13. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers