Ar-Rahman · 12/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ ۝١٢
Walhabbu zul `asfi war Raihaanu
📖 Ni Yorùbá
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 10-14 — Surah Ar-Rahman

10وَالْأَرْضَ وَضَعَهَا لِلْأَنَامِ
Ile, (Allahu) te e sile fun awon eda
11فِيهَا فَاكِهَةٌ وَالنَّخْلُ ذَاتُ الْأَكْمَامِ
Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)
12وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
13فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
14خَلَقَ الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
12Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 12

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 12 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)

Surah Ẹsẹ 12/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 10–14. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers