At-Tahrim · 4/12
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Tahrim
إِن تَتُوبَا إِلَى اللَّهِ فَقَدْ صَغَتْ قُلُوبُكُمَا ۖ وَإِن تَظَاهَرَا عَلَيْهِ فَإِنَّ اللَّهَ هُوَ مَوْلَاهُ وَجِبْرِيلُ وَصَالِحُ الْمُؤْمِنِينَ ۖ وَالْمَلَائِكَةُ بَعْدَ ذَٰلِكَ ظَهِيرٌ ۝٤
In tatoobaaa ilal laahi faqad saghat quloobukumaa wa in tazaaharaa `alihi fa innal laaha huwa mawlaahu wa jibreelu wa saalihul mu`mineen; walma laaa`ikatu ba`dazaalika zaheer
📖 Ni Yorùbá
Ti eyin mejeeji ba ronu piwada si odo Allahu, (O maa gba ironupiwada yin). Sebi okan yin kuku ti te (sibi ki Anabi ma fee Moriyah). Ti e ba si ran ara yin lowo (lati ko ibanuje) ba a, dajudaju Allahu ni Oluranlowo re, ati (molaika) Jibril ati eni rere ninu awon onigbagbo ododo. Leyin iyen, awon molaika ti won je oluranlowo (tun wa fun un)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 2-6 — Surah At-Tahrim

2قَدْ فَرَضَ اللَّهُ لَكُمْ تَحِلَّةَ أَيْمَانِكُمْ ۚ وَاللَّهُ مَوْلَاكُمْ ۖ وَهُوَ الْعَلِيمُ الْحَكِيمُ
Dajudaju Allahu ti se alaye ofin itanran ibura yin fun yin. Allahu ni Oluranlowo yin. Oun si ni Onimo, Ologbon
3وَإِذْ أَسَرَّ النَّبِيُّ إِلَىٰ بَعْضِ أَزْوَاجِهِ حَدِيثًا فَلَمَّا نَبَّأَتْ بِهِ وَأَظْهَرَهُ اللَّهُ عَلَيْهِ عَرَّفَ بَعْضَهُ وَأَعْرَضَ عَن بَعْضٍ ۖ فَلَمَّا نَبَّأَهَا بِهِ قَالَتْ مَنْ أَنبَأَكَ هَٰذَا ۖ قَالَ نَبَّأَنِيَ الْعَلِيمُ الْخَبِيرُ
Ranti nigba ti Anabi ba okan ninu awon iyawo re s’oro asiri. Nigba ti (eni t’o ba soro, iyen Hafsoh) si soro naa fun (‘A’isah), Allahu si fi han Anabi (pe elomiiran ti gbo si i). Anabi si so apa kan re (fun Hafsoh pe: "O ti fi oro Moriyah to ‘A’isah leti."). O si fi apa kan sile (iyen, oro nipa ipo arole). Amo nigba ti (Anabi) fi iro naa to o leti, Hafsoh) so pe: "Ta ni o fun o ni iro eyi?" (Anabi) so pe: "Onimo, Alamotan l’O fun mi ni iro naa
4إِن تَتُوبَا إِلَى اللَّهِ فَقَدْ صَغَتْ قُلُوبُكُمَا ۖ وَإِن تَظَاهَرَا عَلَيْهِ فَإِنَّ اللَّهَ هُوَ مَوْلَاهُ وَجِبْرِيلُ وَصَالِحُ الْمُؤْمِنِينَ ۖ وَالْمَلَائِكَةُ بَعْدَ ذَٰلِكَ ظَهِيرٌ
Ti eyin mejeeji ba ronu piwada si odo Allahu, (O maa gba ironupiwada yin). Sebi okan yin kuku ti te (sibi ki Anabi ma fee Moriyah). Ti e ba si ran ara yin lowo (lati ko ibanuje) ba a, dajudaju Allahu ni Oluranlowo re, ati (molaika) Jibril ati eni rere ninu awon onigbagbo ododo. Leyin iyen, awon molaika ti won je oluranlowo (tun wa fun un)
5عَسَىٰ رَبُّهُ إِن طَلَّقَكُنَّ أَن يُبْدِلَهُ أَزْوَاجًا خَيْرًا مِّنكُنَّ مُسْلِمَاتٍ مُّؤْمِنَاتٍ قَانِتَاتٍ تَائِبَاتٍ عَابِدَاتٍ سَائِحَاتٍ ثَيِّبَاتٍ وَأَبْكَارًا
O see se, ti o ba ko yin sile, ki Oluwa re fi awon obinrin kan, ti won loore ju yin lo ropo fun un, (ti won maa je) musulumi, onigbagbo ododo, awon olutele-ase, awon oluronupiwada, olujosin, olugbaawe ni adelebo ati wundia
6يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا قُوا أَنفُسَكُمْ وَأَهْلِيكُمْ نَارًا وَقُودُهَا النَّاسُ وَالْحِجَارَةُ عَلَيْهَا مَلَائِكَةٌ غِلَاظٌ شِدَادٌ لَّا يَعْصُونَ اللَّهَ مَا أَمَرَهُمْ وَيَفْعَلُونَ مَا يُؤْمَرُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e so emi ara yin ati awon ara ile yin nibi Ina. Eniyan ati okuta ni nnkan ikona re. Awon molaika t’o roro, ti won le ni eso re. Won ko nii yapa ase Allahu nibi ohun ti O ba pa lase fun won. Won si n se ohun ti won ba pa lase fun won
At-TahrimAtokọ Kurani
12Ẹsẹ
MedinanRevelation
4Ẹsẹ

Itumọ — At-Tahrim 4

Surah At-Tahrim Ẹsẹ 4 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti eyin mejeeji ba ronu piwada si odo Allahu, (O…

Surah Ẹsẹ 4/12 — Surah At-Tahrim التحريم (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Tahrim Gbọ, Surah At-Tahrim Itumọ, Surah At-Tahrim mp3, Surah At-Tahrim pdf. Ẹsẹ 2–6. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers