Al-Qalam · 3/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
وَإِنَّ لَكَ لَأَجْرًا غَيْرَ مَمْنُونٍ ۝٣
Wa inna laka la ajran ghaira mamnoon
📖 Ni Yorùbá
Ati pe dajudaju esan ti ko nii dawo duro ti wa fun o

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 1-5 — Surah Al-Qalam

1ن ۚ وَالْقَلَمِ وَمَا يَسْطُرُونَ
Nun. (Allahu bura pelu) gege ikowe ati ohun ti awon molaika n ko sile
2مَا أَنتَ بِنِعْمَةِ رَبِّكَ بِمَجْنُونٍ
Iwo ki i se were nipa idera Oluwa re
3وَإِنَّ لَكَ لَأَجْرًا غَيْرَ مَمْنُونٍ
Ati pe dajudaju esan ti ko nii dawo duro ti wa fun o
4وَإِنَّكَ لَعَلَىٰ خُلُقٍ عَظِيمٍ
Dajudaju iwo si wa lori iwa aponle
5فَسَتُبْصِرُ وَيُبْصِرُونَ
Laipe iwo yoo ri i, awon naa yo si ri i
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
3Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 3

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 3 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe dajudaju esan ti ko nii dawo duro ti…

Surah Ẹsẹ 3/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 1–5. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers