Al-Qalam · 5/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Qalam
فَسَتُبْصِرُ وَيُبْصِرُونَ ۝٥
Fasatubsiru wa yubsiroon
📖 Ni Yorùbá
Laipe iwo yoo ri i, awon naa yo si ri i
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 3-7 — Al-Qalam

3وَإِنَّ لَكَ لَأَجْرًا غَيْرَ مَمْنُونٍ
Ati pe dajudaju esan ti ko nii dawo duro ti wa fun o
4وَإِنَّكَ لَعَلَىٰ خُلُقٍ عَظِيمٍ
Dajudaju iwo si wa lori iwa aponle
5فَسَتُبْصِرُ وَيُبْصِرُونَ
Laipe iwo yoo ri i, awon naa yo si ri i
6بِأَييِّكُمُ الْمَفْتُونُ
ewo ninu yin ni were
7إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعْلَمُ بِمَن ضَلَّ عَن سَبِيلِهِ وَهُوَ أَعْلَمُ بِالْمُهْتَدِينَ
Dajudaju Oluwa re, O nimo julo nipa eni t’o sina kuro loju ona Re. O si nimo julo nipa awon olumona
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
5Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 5

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 5 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Laipe iwo yoo ri i, awon naa yo si ri…

Surah Ẹsẹ 5/52 — Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Qalam Gbọ, Al-Qalam Itumọ, Al-Qalam mp3, Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 3–7. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers