Surah Al-Buruj ni Arabic ati Yorùbá
Ka Surah Al-Buruj pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (22 Ẹsẹ — مكية). Al-Buruj Gbọ, Al-Buruj Itumọ, Al-Buruj mp3, Al-Buruj pdf.Ka ati Gbọ Surah Al-Buruj
🎧 Ẹsẹ
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
—
x1
وَالسَّمَاءِ ذَاتِ الْبُرُوجِ ١
📖 Itumọ
Ẹsẹ 1
(Allahu) bura pelu sanmo ti awon ibuso (oorun, osupa ati awon irawo) wa ninu re
وَهُمْ عَلَىٰ مَا يَفْعَلُونَ بِالْمُؤْمِنِينَ شُهُودٌ ٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 7
Won si n wo ohun ti won n se fun awon onigbagbo ododo
وَمَا نَقَمُوا مِنْهُمْ إِلَّا أَن يُؤْمِنُوا بِاللَّهِ الْعَزِيزِ الْحَمِيدِ ٨
📖 Itumọ
Ẹsẹ 8
Ko si si kini kan ti won tori re je won niya bi ko se pe won ni igbagbo ododo ninu Allahu, Alagbara, Olope
الَّذِي لَهُ مُلْكُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَاللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ شَهِيدٌ ٩
📖 Itumọ
Ẹsẹ 9
Eni ti O ni ijoba awon sanmo ati ile. Allahu si ni Elerii lori gbogbo nnkan
إِنَّ الَّذِينَ فَتَنُوا الْمُؤْمِنِينَ وَالْمُؤْمِنَاتِ ثُمَّ لَمْ يَتُوبُوا فَلَهُمْ عَذَابُ جَهَنَّمَ وَلَهُمْ عَذَابُ الْحَرِيقِ ١٠
📖 Itumọ
Ẹsẹ 10
Dajudaju awon t’o fi inira kan awon onigbagbo ododo lokunrin ati awon onigbagbo ododo lobinrin, leyin naa ti won ko ronu piwada, iya ina Jahanamo n be fun won. Iya ina t’o n jo si wa fun won
إِنَّ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ لَهُمْ جَنَّاتٌ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ ۚ ذَٰلِكَ الْفَوْزُ الْكَبِيرُ ١١
📖 Itumọ
Ẹsẹ 11
Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, tiwon ni awon Ogba Idera kan, ti awon odo n san ni isale re. Iyen si ni erenje nla
إِنَّهُ هُوَ يُبْدِئُ وَيُعِيدُ ١٣
📖 Itumọ
Ẹsẹ 13
Dajudaju Oun ni O pile (eda), O si maa da (eda) pada (fun ajinde)
بَلِ الَّذِينَ كَفَرُوا فِي تَكْذِيبٍ ١٩
📖 Itumọ
Ẹsẹ 19
Sibesibe awon t’o sai gbagbo si n pe ododo niro
بَلْ هُوَ قُرْآنٌ مَّجِيدٌ ٢١
📖 Itumọ
Ẹsẹ 21
Amo sa, ohun (ti A fi ranse si o ni) al-Ƙur’an alapon-onle
Kika Surah Al-Buruj ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers

