Taha · 97/135
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Taha
قَالَ فَاذْهَبْ فَإِنَّ لَكَ فِي الْحَيَاةِ أَن تَقُولَ لَا مِسَاسَ ۖ وَإِنَّ لَكَ مَوْعِدًا لَّن تُخْلَفَهُ ۖ وَانظُرْ إِلَىٰ إِلَٰهِكَ الَّذِي ظَلْتَ عَلَيْهِ عَاكِفًا ۖ لَّنُحَرِّقَنَّهُ ثُمَّ لَنَنسِفَنَّهُ فِي الْيَمِّ نَسْفًا ۝٩٧
Qaala fazhab fa inna laka fil hayaati an taqoola laa misaasa wa inna laka maw`idal lan tukhlafahoo wanzur ilaaa ilaahikal lazee zalta `alaihi `aakifaa; lanuharriqannnahoo summa lanansifanahoo fil yammi nasfaa
📖 Ni Yorùbá
(Anabi Musa) so pe: “Nitori naa, maa lo. Dajudaju (ijiya) re nile aye yii ni ki o maa wi pe, “Ma fi ara kan mi”. Ati pe dajudaju ojo iya kan n be fun o ti Won ko nii gbe fo o. Ki o si wo olohun re, eyi ti o taku ti lorun, dajudaju a maa dana sun un. Leyin naa, dajudaju a maa ku eeru re danu patapata sinu agbami odo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 95-99 — Surah Taha

95قَالَ فَمَا خَطْبُكَ يَا سَامِرِيُّ
(Anabi Musa) so pe: “Ki ni oro tire ti je, Samiriyy?”
96قَالَ بَصُرْتُ بِمَا لَمْ يَبْصُرُوا بِهِ فَقَبَضْتُ قَبْضَةً مِّنْ أَثَرِ الرَّسُولِ فَنَبَذْتُهَا وَكَذَٰلِكَ سَوَّلَتْ لِي نَفْسِي
(Samiriyy) wi pe: “Mo ri ohun ti won ko ri. Mo si bu ekunwo kan nibi (erupe) oju ese (esin) Ojise (iyen, molaika Jibril). Mo si da a sile (lati fi mo ere). Bayen ni emi mi se (aburu) ni oso fun mi.”
97قَالَ فَاذْهَبْ فَإِنَّ لَكَ فِي الْحَيَاةِ أَن تَقُولَ لَا مِسَاسَ ۖ وَإِنَّ لَكَ مَوْعِدًا لَّن تُخْلَفَهُ ۖ وَانظُرْ إِلَىٰ إِلَٰهِكَ الَّذِي ظَلْتَ عَلَيْهِ عَاكِفًا ۖ لَّنُحَرِّقَنَّهُ ثُمَّ لَنَنسِفَنَّهُ فِي الْيَمِّ نَسْفًا
(Anabi Musa) so pe: “Nitori naa, maa lo. Dajudaju (ijiya) re nile aye yii ni ki o maa wi pe, “Ma fi ara kan mi”. Ati pe dajudaju ojo iya kan n be fun o ti Won ko nii gbe fo o. Ki o si wo olohun re, eyi ti o taku ti lorun, dajudaju a maa dana sun un. Leyin naa, dajudaju a maa ku eeru re danu patapata sinu agbami odo
98إِنَّمَا إِلَٰهُكُمُ اللَّهُ الَّذِي لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ ۚ وَسِعَ كُلَّ شَيْءٍ عِلْمًا
Olohun yin ni Allahu nikan, ko si olohun ti ijosin to si afi Oun. O fi imo gbooro ju gbogbo nnkan
99كَذَٰلِكَ نَقُصُّ عَلَيْكَ مِنْ أَنبَاءِ مَا قَدْ سَبَقَ ۚ وَقَدْ آتَيْنَاكَ مِن لَّدُنَّا ذِكْرًا
Bayen ni A se n so itan fun o ninu awon iro ti o ti siwaju. Lati odo Wa si ni A kuku ti fun o ni iranti (iyen, al-Ƙur’an)
TahaAtokọ Kurani
135Ẹsẹ
MeccanRevelation
97Ẹsẹ

Itumọ — Taha 97

Surah Taha Ẹsẹ 97 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Anabi Musa) so pe: “Nitori naa, maa lo. Dajudaju (ijiya)…

Surah Ẹsẹ 97/135 — Surah Taha طه (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Taha Gbọ, Surah Taha Itumọ, Surah Taha mp3, Surah Taha pdf. Ẹsẹ 95–99. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers