Al-Hajj · 12/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Hajj
يَدْعُو مِن دُونِ اللَّهِ مَا لَا يَضُرُّهُ وَمَا لَا يَنفَعُهُ ۚ ذَٰلِكَ هُوَ الضَّلَالُ الْبَعِيدُ ١٢
Transliteration
Yad`oo min doonil laahi maa laa yadurruhoo wa maa laa yanfa`uh` zaalika huwad dalaalul ba`ed
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
O n pe leyin Allahu ohun ti ko le ko inira ba a, ti ko si le se e ni oore; iyen ni isina t’o jinna (si imona)
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 10-14 — Al-Hajj
10ذَٰلِكَ بِمَا قَدَّمَتْ يَدَاكَ وَأَنَّ اللَّهَ لَيْسَ بِظَلَّامٍ لِّلْعَبِيدِ
Iyen nitori ohun ti owo re ti siwaju. Dajudaju Allahu ko nii sabosi si awon erusin Re
11وَمِنَ النَّاسِ مَن يَعْبُدُ اللَّهَ عَلَىٰ حَرْفٍ ۖ فَإِنْ أَصَابَهُ خَيْرٌ اطْمَأَنَّ بِهِ ۖ وَإِنْ أَصَابَتْهُ فِتْنَةٌ انقَلَبَ عَلَىٰ وَجْهِهِ خَسِرَ الدُّنْيَا وَالْآخِرَةَ ۚ ذَٰلِكَ هُوَ الْخُسْرَانُ الْمُبِينُ
O tun wa ninu awon eniyan eni t’o n josin fun Allahu lori ahon. Ti rere ba sele si i, o maa fi okan bale (sinu esin). Ti ifooro ba si sele si i, o maa yiju re pada kuro ninu esin. O sofo laye ati lorun. Iyen ni ofo ponnbele
12يَدْعُو مِن دُونِ اللَّهِ مَا لَا يَضُرُّهُ وَمَا لَا يَنفَعُهُ ۚ ذَٰلِكَ هُوَ الضَّلَالُ الْبَعِيدُ
O n pe leyin Allahu ohun ti ko le ko inira ba a, ti ko si le se e ni oore; iyen ni isina t’o jinna (si imona)
13يَدْعُو لَمَن ضَرُّهُ أَقْرَبُ مِن نَّفْعِهِ ۚ لَبِئْسَ الْمَوْلَىٰ وَلَبِئْسَ الْعَشِيرُ
O n pe ohun ti inira re sunmo ju anfaani re lo. Dajudaju (orisa) buru ni oluranlowo, o si buru ni alasun-unmo
14إِنَّ اللَّهَ يُدْخِلُ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ ۚ إِنَّ اللَّهَ يَفْعَلُ مَا يُرِيدُ
Dajudaju Allahu yoo mu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere wo inu Ogba Idera ti awon odo n san ni isale re. Dajudaju Allahu n se ohun ti O ba fe
Al-HajjAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
12Ẹsẹ
Itumọ — Al-Hajj 12
Surah Al-Hajj Ẹsẹ 12 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : O n pe leyin Allahu ohun ti ko le ko…Surah Ẹsẹ 12/78 — Al-Hajj الحج (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Hajj Gbọ, Al-Hajj Itumọ, Al-Hajj mp3, Al-Hajj pdf. Ẹsẹ 10–14. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








