An-Nur · 47/64
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah An-Nur
وَيَقُولُونَ آمَنَّا بِاللَّهِ وَبِالرَّسُولِ وَأَطَعْنَا ثُمَّ يَتَوَلَّىٰ فَرِيقٌ مِّنْهُم مِّن بَعْدِ ذَٰلِكَ ۚ وَمَا أُولَٰئِكَ بِالْمُؤْمِنِينَ ٤٧
Transliteration
Wa yaqooloona aamannaa billaahi wa bir Rasooli wa ata`naa summa yatawallaa fareequm minhum mim ba`di zaalik; wa maaa ulaaa`ika bilmu`mineen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Won n wi pe: “A gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re. A si tele (ase Won).” Leyin naa, igun kan ninu won n peyin da leyin iyen. Awon wonyen ki i se onigbagbo ododo
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 45-49 — Surah An-Nur
45وَاللَّهُ خَلَقَ كُلَّ دَابَّةٍ مِّن مَّاءٍ ۖ فَمِنْهُم مَّن يَمْشِي عَلَىٰ بَطْنِهِ وَمِنْهُم مَّن يَمْشِي عَلَىٰ رِجْلَيْنِ وَمِنْهُم مَّن يَمْشِي عَلَىٰ أَرْبَعٍ ۚ يَخْلُقُ اللَّهُ مَا يَشَاءُ ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Allahu seda gbogbo abemi lati inu omi. O wa ninu won, eyi t’o n fi aya re wo. O wa ninu won, eyi t’o n fi ese meji rin. O si wa ninu won, eyi t’o n fi merin rin. Allahu n seda ohun ti O ba fe. Dajudaju Allahu ni Alagbara lori gbogbo nnkan
46لَّقَدْ أَنزَلْنَا آيَاتٍ مُّبَيِّنَاتٍ ۚ وَاللَّهُ يَهْدِي مَن يَشَاءُ إِلَىٰ صِرَاطٍ مُّسْتَقِيمٍ
Dajudaju A ti so awon ayah t’o n yanju oro kale. Allahu si n to enikeni ti O ba fe si ona taara (’Islam)
47وَيَقُولُونَ آمَنَّا بِاللَّهِ وَبِالرَّسُولِ وَأَطَعْنَا ثُمَّ يَتَوَلَّىٰ فَرِيقٌ مِّنْهُم مِّن بَعْدِ ذَٰلِكَ ۚ وَمَا أُولَٰئِكَ بِالْمُؤْمِنِينَ
Won n wi pe: “A gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re. A si tele (ase Won).” Leyin naa, igun kan ninu won n peyin da leyin iyen. Awon wonyen ki i se onigbagbo ododo
48وَإِذَا دُعُوا إِلَى اللَّهِ وَرَسُولِهِ لِيَحْكُمَ بَيْنَهُمْ إِذَا فَرِيقٌ مِّنْهُم مُّعْرِضُونَ
Ati pe nigba ti won ba pe won si ti Allahu ati ti Ojise Re nitori ki o le sedajo laaarin won, nigba naa ni igun kan ninu won yoo maa gbunri
49وَإِن يَكُن لَّهُمُ الْحَقُّ يَأْتُوا إِلَيْهِ مُذْعِنِينَ
Ti o ba si je pe awon ni won ni eto (are) ni, won yoo wa ba o ni tokan-tara
An-NurAtokọ Kurani
64Ẹsẹ
MedinanRevelation
47Ẹsẹ
Itumọ — An-Nur 47
Surah An-Nur Ẹsẹ 47 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won n wi pe: “A gbagbo ninu Allahu ati Ojise…Surah Ẹsẹ 47/64 — Surah An-Nur النور (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah An-Nur Gbọ, Surah An-Nur Itumọ, Surah An-Nur mp3, Surah An-Nur pdf. Ẹsẹ 45–49. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








