Aal-Imran · 56/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
فَأَمَّا الَّذِينَ كَفَرُوا فَأُعَذِّبُهُمْ عَذَابًا شَدِيدًا فِي الدُّنْيَا وَالْآخِرَةِ وَمَا لَهُم مِّن نَّاصِرِينَ ٥٦
Transliteration
Fa ammal lazeena kafaroo fa u`az zibuhum `azaaban shadeedan fiddunyaa wal Aakhirati wa maa lahum min naasireen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Ni ti awon t’o sai gbagbo, Emi yoo je won niya lile ni aye ati ni orun. Ko si nii si awon oluranlowo fun won
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 54-58 — Surah Aal-Imran
54وَمَكَرُوا وَمَكَرَ اللَّهُ ۖ وَاللَّهُ خَيْرُ الْمَاكِرِينَ
Won dete, Allahu si dete. Allahu si l’oore julo ninu awon adete
55إِذْ قَالَ اللَّهُ يَا عِيسَىٰ إِنِّي مُتَوَفِّيكَ وَرَافِعُكَ إِلَيَّ وَمُطَهِّرُكَ مِنَ الَّذِينَ كَفَرُوا وَجَاعِلُ الَّذِينَ اتَّبَعُوكَ فَوْقَ الَّذِينَ كَفَرُوا إِلَىٰ يَوْمِ الْقِيَامَةِ ۖ ثُمَّ إِلَيَّ مَرْجِعُكُمْ فَأَحْكُمُ بَيْنَكُمْ فِيمَا كُنتُمْ فِيهِ تَخْتَلِفُونَ
Wafat/wafah si tumo si ""ƙobd"" gbigba eni kan kuro lowo eni kan ninu surah ali ‘Imron 3:55 ati surah al-Mo’dah elesin ’Islam ni awon t’o tele ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam). Ati ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ati owo awon t’o tele e loju aye re musulumi ni won gege bi won se pera won bee ninu surah yii
56فَأَمَّا الَّذِينَ كَفَرُوا فَأُعَذِّبُهُمْ عَذَابًا شَدِيدًا فِي الدُّنْيَا وَالْآخِرَةِ وَمَا لَهُم مِّن نَّاصِرِينَ
Ni ti awon t’o sai gbagbo, Emi yoo je won niya lile ni aye ati ni orun. Ko si nii si awon oluranlowo fun won
57وَأَمَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ فَيُوَفِّيهِمْ أُجُورَهُمْ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ الظَّالِمِينَ
Ni ti awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, (Allahu) maa fun won ni esan won ni kikun. Allahu ko si feran awon alabosi
58ذَٰلِكَ نَتْلُوهُ عَلَيْكَ مِنَ الْآيَاتِ وَالذِّكْرِ الْحَكِيمِ
Iyen ni A n ke fun o ninu awon ayah ati iranti ti o kun fun ogbon ijinle (iyen, al-Ƙur’an)
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
56Ẹsẹ
Itumọ — Aal-Imran 56
Surah Aal-Imran Ẹsẹ 56 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ni ti awon t’o sai gbagbo, Emi yoo je won…Surah Ẹsẹ 56/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 54–58. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Monday, September 7, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








