At-Taghabun · 17/18
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah At-Taghabun
إِن تُقْرِضُوا اللَّهَ قَرْضًا حَسَنًا يُضَاعِفْهُ لَكُمْ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ۚ وَاللَّهُ شَكُورٌ حَلِيمٌ ۝١٧
In tuqridul laaha qardan hasanany yudd`ifhu lakum wa yaghfir lakum; wallaahu Shakoorun Haleem
📖 Ni Yorùbá
Ti e ba ya Allahu ni dukia t’o dara, O maa sadipele re fun yin. O si maa forijin yin. Allahu si ni Olumoore, Alafarada

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 15-18 — Surah At-Taghabun

15إِنَّمَا أَمْوَالُكُمْ وَأَوْلَادُكُمْ فِتْنَةٌ ۚ وَاللَّهُ عِندَهُ أَجْرٌ عَظِيمٌ
Ifooro ni awon dukia yin ati awon omo yin. Allahu si ni esan nla wa ni odo Re
16فَاتَّقُوا اللَّهَ مَا اسْتَطَعْتُمْ وَاسْمَعُوا وَأَطِيعُوا وَأَنفِقُوا خَيْرًا لِّأَنفُسِكُمْ ۗ وَمَن يُوقَ شُحَّ نَفْسِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ
Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara mo. E gbo oro (Allahu), e tele e, ki e si nawo (fun esin Re) loore julo fun emi yin. Enikeni ti A ba so nibi ahun ati okanjua inu emi re, awon wonyen, awon ni olujere
17إِن تُقْرِضُوا اللَّهَ قَرْضًا حَسَنًا يُضَاعِفْهُ لَكُمْ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ۚ وَاللَّهُ شَكُورٌ حَلِيمٌ
Ti e ba ya Allahu ni dukia t’o dara, O maa sadipele re fun yin. O si maa forijin yin. Allahu si ni Olumoore, Alafarada
18عَالِمُ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Onimo-ikoko ati gbangba, Alagbara, Ologbon
At-TaghabunAtokọ Kurani
18Ẹsẹ
MedinanRevelation
17Ẹsẹ

Itumọ — At-Taghabun 17

Surah At-Taghabun Ẹsẹ 17 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti e ba ya Allahu ni dukia t’o dara, O…

Surah Ẹsẹ 17/18 — Surah At-Taghabun التغابن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah At-Taghabun Gbọ, Surah At-Taghabun Itumọ, Surah At-Taghabun mp3, Surah At-Taghabun pdf. Ẹsẹ 15–18. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers