At-Taghabun · 18/18
Itumọ Aṣẹ ohun — At-Taghabun
عَالِمُ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ ۝١٨
Aalimul-Ghaibi wash-shahaadatil `Azeezul Hakeem
📖 Ni Yorùbá
Onimo-ikoko ati gbangba, Alagbara, Ologbon
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 16-18 — At-Taghabun

16فَاتَّقُوا اللَّهَ مَا اسْتَطَعْتُمْ وَاسْمَعُوا وَأَطِيعُوا وَأَنفِقُوا خَيْرًا لِّأَنفُسِكُمْ ۗ وَمَن يُوقَ شُحَّ نَفْسِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ
Nitori naa, e beru Allahu bi e ba se lagbara mo. E gbo oro (Allahu), e tele e, ki e si nawo (fun esin Re) loore julo fun emi yin. Enikeni ti A ba so nibi ahun ati okanjua inu emi re, awon wonyen, awon ni olujere
17إِن تُقْرِضُوا اللَّهَ قَرْضًا حَسَنًا يُضَاعِفْهُ لَكُمْ وَيَغْفِرْ لَكُمْ ۚ وَاللَّهُ شَكُورٌ حَلِيمٌ
Ti e ba ya Allahu ni dukia t’o dara, O maa sadipele re fun yin. O si maa forijin yin. Allahu si ni Olumoore, Alafarada
18عَالِمُ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Onimo-ikoko ati gbangba, Alagbara, Ologbon
At-TaghabunAtokọ Kurani
18Ẹsẹ
MedinanRevelation
18Ẹsẹ

Itumọ — At-Taghabun 18

Surah At-Taghabun Ẹsẹ 18 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Onimo-ikoko ati gbangba, Alagbara, Ologbon

Surah Ẹsẹ 18/18 — At-Taghabun التغابن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: At-Taghabun Gbọ, At-Taghabun Itumọ, At-Taghabun mp3, At-Taghabun pdf. Ẹsẹ 16–18. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers