Al-Mulk · 1/30
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Mulk
تَبَارَكَ الَّذِي بِيَدِهِ الْمُلْكُ وَهُوَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ ۝١
Tabaarakal lazee biyadihil mulku wa huwa `alaa kulli shai-in qadeer
📖 Ni Yorùbá
Ibukun ni fun Eni ti ijoba wa ni Owo Re. Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 1-3 — Surah Al-Mulk

1تَبَارَكَ الَّذِي بِيَدِهِ الْمُلْكُ وَهُوَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Ibukun ni fun Eni ti ijoba wa ni Owo Re. Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan
2الَّذِي خَلَقَ الْمَوْتَ وَالْحَيَاةَ لِيَبْلُوَكُمْ أَيُّكُمْ أَحْسَنُ عَمَلًا ۚ وَهُوَ الْعَزِيزُ الْغَفُورُ
Eni ti O da iku ati isemi nitori ki o le dan yin wo; ewo ninu yin l’o maa se ise rere julo. Oun si ni Alagbara, Alaforijin
3الَّذِي خَلَقَ سَبْعَ سَمَاوَاتٍ طِبَاقًا ۖ مَّا تَرَىٰ فِي خَلْقِ الرَّحْمَٰنِ مِن تَفَاوُتٍ ۖ فَارْجِعِ الْبَصَرَ هَلْ تَرَىٰ مِن فُطُورٍ
Eni ti O da awon sanmo meje ni ipele ipele. O o le ri aigunrege kan lara eda Ajoke-aye. Nitori naa, wo o pada, nje o ri oju sisan kan (lara sanmo)
Al-MulkAtokọ Kurani
30Ẹsẹ
MeccanRevelation
1Ẹsẹ

Itumọ — Al-Mulk 1

Surah Al-Mulk Ẹsẹ 1 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ibukun ni fun Eni ti ijoba wa ni Owo Re.…

Surah Ẹsẹ 1/30 — Surah Al-Mulk الملك (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Mulk Gbọ, Surah Al-Mulk Itumọ, Surah Al-Mulk mp3, Surah Al-Mulk pdf. Ẹsẹ 1–3. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers