Al-Qalam · 46/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
أَمْ تَسْأَلُهُمْ أَجْرًا فَهُم مِّن مَّغْرَمٍ مُّثْقَلُونَ ۝٤٦
Am tas`aluhum ajran fahum mim maghramim musqaloon
📖 Ni Yorùbá
Tabi o n beere owo-oya kan lodo won, ni gbese fi wo won lorun

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 44-48 — Surah Al-Qalam

44فَذَرْنِي وَمَن يُكَذِّبُ بِهَٰذَا الْحَدِيثِ ۖ سَنَسْتَدْرِجُهُم مِّنْ حَيْثُ لَا يَعْلَمُونَ
Nitori naa, fi Emi ati eni t’o n pe oro yii niro sile. A oo maa de won leke lati je won niya ni aye ti won ko mo
45وَأُمْلِي لَهُمْ ۚ إِنَّ كَيْدِي مَتِينٌ
Mo n lora fun won ni. Dajudaju ete Mi lagbara
46أَمْ تَسْأَلُهُمْ أَجْرًا فَهُم مِّن مَّغْرَمٍ مُّثْقَلُونَ
Tabi o n beere owo-oya kan lodo won, ni gbese fi wo won lorun
47أَمْ عِندَهُمُ الْغَيْبُ فَهُمْ يَكْتُبُونَ
Tabi lodo won ni (walaa) ikoko wa ni won ba n ko o (sita)
48فَاصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ وَلَا تَكُن كَصَاحِبِ الْحُوتِ إِذْ نَادَىٰ وَهُوَ مَكْظُومٌ
Nitori naa, se suuru fun idajo Oluwa re. Ki iwo ma si se da bi eleja (iyen, Anabi Yunus) nigba ti o pe (Allahu) pelu ibanuje
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
46Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 46

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 46 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Tabi o n beere owo-oya kan lodo won, ni gbese…

Surah Ẹsẹ 46/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 44–48. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers