Al-Qalam · 47/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
أَمْ عِندَهُمُ الْغَيْبُ فَهُمْ يَكْتُبُونَ ۝٤٧
Am `indahumul ghaibu fahum yaktuboon
📖 Ni Yorùbá
Tabi lodo won ni (walaa) ikoko wa ni won ba n ko o (sita)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 45-49 — Surah Al-Qalam

45وَأُمْلِي لَهُمْ ۚ إِنَّ كَيْدِي مَتِينٌ
Mo n lora fun won ni. Dajudaju ete Mi lagbara
46أَمْ تَسْأَلُهُمْ أَجْرًا فَهُم مِّن مَّغْرَمٍ مُّثْقَلُونَ
Tabi o n beere owo-oya kan lodo won, ni gbese fi wo won lorun
47أَمْ عِندَهُمُ الْغَيْبُ فَهُمْ يَكْتُبُونَ
Tabi lodo won ni (walaa) ikoko wa ni won ba n ko o (sita)
48فَاصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ وَلَا تَكُن كَصَاحِبِ الْحُوتِ إِذْ نَادَىٰ وَهُوَ مَكْظُومٌ
Nitori naa, se suuru fun idajo Oluwa re. Ki iwo ma si se da bi eleja (iyen, Anabi Yunus) nigba ti o pe (Allahu) pelu ibanuje
49لَّوْلَا أَن تَدَارَكَهُ نِعْمَةٌ مِّن رَّبِّهِ لَنُبِذَ بِالْعَرَاءِ وَهُوَ مَذْمُومٌ
Ti ko ba je pe ike kan lati odo Oluwa re le e ba, won iba ju u sori ile gbansasa (lati inu eja) ni eni-eebu
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
47Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 47

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 47 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Tabi lodo won ni (walaa) ikoko wa ni won ba…

Surah Ẹsẹ 47/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 45–49. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers