Al-Qalam · 45/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
وَأُمْلِي لَهُمْ ۚ إِنَّ كَيْدِي مَتِينٌ ۝٤٥
Wa umlee lahum; inna kaidee mateen
📖 Ni Yorùbá
Mo n lora fun won ni. Dajudaju ete Mi lagbara

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 43-47 — Surah Al-Qalam

43خَاشِعَةً أَبْصَارُهُمْ تَرْهَقُهُمْ ذِلَّةٌ ۖ وَقَدْ كَانُوا يُدْعَوْنَ إِلَى السُّجُودِ وَهُمْ سَالِمُونَ
Oju won yoo wale. Iyepere maa bo won mole. Won kuku ti pe won sibi iforikanle nigba ti won ni alaafia (won ko si kirun)
44فَذَرْنِي وَمَن يُكَذِّبُ بِهَٰذَا الْحَدِيثِ ۖ سَنَسْتَدْرِجُهُم مِّنْ حَيْثُ لَا يَعْلَمُونَ
Nitori naa, fi Emi ati eni t’o n pe oro yii niro sile. A oo maa de won leke lati je won niya ni aye ti won ko mo
45وَأُمْلِي لَهُمْ ۚ إِنَّ كَيْدِي مَتِينٌ
Mo n lora fun won ni. Dajudaju ete Mi lagbara
46أَمْ تَسْأَلُهُمْ أَجْرًا فَهُم مِّن مَّغْرَمٍ مُّثْقَلُونَ
Tabi o n beere owo-oya kan lodo won, ni gbese fi wo won lorun
47أَمْ عِندَهُمُ الْغَيْبُ فَهُمْ يَكْتُبُونَ
Tabi lodo won ni (walaa) ikoko wa ni won ba n ko o (sita)
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
45Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 45

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 45 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Mo n lora fun won ni. Dajudaju ete Mi lagbara

Surah Ẹsẹ 45/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 43–47. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers