PDF —
20 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Al-Balad pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Al-Balad pdf Yorùbá — Gbà Surah Al-Balad Itumọ. Surah Al-Balad (Meccan) 20 Ẹsẹ.

← Al-FajrSurah Al-Balad Ash-Shams →


20 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭽﭾﭿﮀﮁ
90:1 Emi (Allahu) bura pelu ilu yii
ﮂﮃﮄﮅﮆ
90:2 Iwo si ni eto si ilu yii (lati jagun ninu re)
ﮇﮈﮉﮊ
90:3 (Mo tun) bura pelu obi ati ohun t’o bi
ﮋﮌﮍﮎﮏﮐ
90:4 Dajudaju A seda eniyan sinu isoro
ﮑﮒﮓﮔﮕﮖﮗ
90:5 Se o n lero pe eni kan ko ni agbara lori oun ni
ﮘﮙﮚﮛﮜ
90:6 O (si) n wi pe: "Emi ti bana dukia opolopo (lati fi tako Anabi s.a.w)
ﮝﮞﮟﮠﮡﮢ
90:7 Se o n lero pe eni kan ko ri oun ni
ﮣﮤﮥﮦﮧ
90:8 Se A ko se oju meji fun un
ﮨﮩﮪ
90:9 Ati ahon pelu ete meji (ti A se fun un)
ﮫﮬﮭ
90:10 A si fi ona meji mo on
ﮮﮯﮰﮱ
90:11 Ko si mu akaba igbala gun
ﯓﯔﯕﯖﯗ
90:12 Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je akaba igbala
ﯘﯙﯚ
90:13 (Ohun ni) titu eru sile loko eru
ﯛﯜﯝﯞﯟﯠﯡ
90:14 Tabi fifun eniyan ni ounje ni ojo ebi
ﯢﯣﯤﯥ
90:15 (O le je) omo-orukan ninu ebi
ﯦﯧﯨﯩﯪ
90:16 tabi mekunnu, eni ileele
ﯫﯬﯭﯮﯯﯰﯱﯲﯳﯴ
90:17 Leyin naa, ki o wa ninu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won n gbara won niyanju suuru sise, ti won si tun n gbara won niyanju aanu sise
ﯵﯶﯷﯸ
90:18 Awon wonyen ni ero owo otun
ﭑﭒﭓﭔﭕﭖﭗ
90:19 Awon t’o si sai gbagbo ninu awon ayah Wa, awon ni ero owo osi
ﭘﭙﭚﭛ
90:20 A maa ti awon ilekun Ina pa mo won lori patapata

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers