PDF —
15 Ẹsẹ Meccan PDF
Built right in your browser — download starts automatically

Surah Ash-Shams pdf — Gbà (Yorùbá)

Surah Ash-Shams pdf Yorùbá — Gbà Surah Ash-Shams Itumọ. Surah Ash-Shams (Meccan) 15 Ẹsẹ.

← Al-BaladSurah Ash-Shams Al-Layl →


15 Ẹsẹ · Meccan · Yorùbá
bismillah
ﭜﭝﭞ
91:1 (Allahu) bura pelu oorun ati iyaleta re
ﭟﭠﭡﭢ
91:2 O tun bura pelu osupa nigba ti o ba (yo) tele (oorun)
ﭣﭤﭥﭦ
91:3 O tun bura pelu osan nigba ti o ba mu imole ba okunkun oru
ﭧﭨﭩﭪ
91:4 O tun bura pelu ale nigba ti o ba bo osan mole
ﭫﭬﭭﭮ
91:5 O tun bura pelu sanmo ati Eni ti O mo on
ﭯﭰﭱﭲ
91:6 O tun bura pelu ile ati Eni ti O te e kale
ﭳﭴﭵﭶ
91:7 O tun bura pelu emi (eniyan) ati Eni ti O se (orikee re) dogba
ﭷﭸﭹﭺ
91:8 O si fi ese (ti emi le da) ati iberu re mo on
ﭻﭼﭽﭾﭿ
91:9 Enikeni ti o ba safomo (emi ara) re (nibi ese), o ma ti jere
ﮀﮁﮂﮃﮄ
91:10 Enikeni ti o ba fi (iwa ese) ba emi (ara) re je, o ma ti padanu
ﮅﮆﮇﮈ
91:11 Ijo Thamud pe ododo niro nipa itayo enu-ala won
ﮉﮊﮋﮌ
91:12 (Ranti) nigba ti eni ti ori re buru julo ninu won sare dide (lati gun rakunmi pa)
ﮍﮎﮏﮐﮑﮒﮓﮔ
91:13 Nigba naa, Ojise Allahu so fun won pe: "(E fi) abo rakunmi Allahu ati omi re (sile)
ﮕﮖﮗﮘﮙﮚﮛﮜ
91:14 Won pe e niro. Won si gun (rakunmi) pa. Nitori naa, Oluwa won pa won re nitori ese won. O si fi iparun naa kari won
ﮝﮞﮟﮠ
91:15 (Eni t’o gun rakunmi pa) ko si paya ikangun oro won

Al-Kur'an


Wednesday, September 9, 2026

Don't forget us in your sincere prayers