Surah Al-Balad ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Balad pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (20 Ẹsẹ — مكية). Al-Balad Gbọ, Al-Balad Itumọ, Al-Balad mp3, Al-Balad pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Balad

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
لَا أُقْسِمُ بِهَٰذَا الْبَلَدِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Emi (Allahu) bura pelu ilu yii
وَأَنتَ حِلٌّ بِهَٰذَا الْبَلَدِ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Iwo si ni eto si ilu yii (lati jagun ninu re)
وَوَالِدٍ وَمَا وَلَدَ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
(Mo tun) bura pelu obi ati ohun t’o bi
لَقَدْ خَلَقْنَا الْإِنسَانَ فِي كَبَدٍ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Dajudaju A seda eniyan sinu isoro
أَيَحْسَبُ أَن لَّن يَقْدِرَ عَلَيْهِ أَحَدٌ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Se o n lero pe eni kan ko ni agbara lori oun ni
يَقُولُ أَهْلَكْتُ مَالًا لُّبَدًا ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
O (si) n wi pe: "Emi ti bana dukia opolopo (lati fi tako Anabi s.a.w)
أَيَحْسَبُ أَن لَّمْ يَرَهُ أَحَدٌ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
Se o n lero pe eni kan ko ri oun ni
أَلَمْ نَجْعَل لَّهُ عَيْنَيْنِ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
Se A ko se oju meji fun un
وَلِسَانًا وَشَفَتَيْنِ ۝٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 9
Ati ahon pelu ete meji (ti A se fun un)
وَهَدَيْنَاهُ النَّجْدَيْنِ ۝١٠
📖 Itumọ Ẹsẹ 10
A si fi ona meji mo on
فَلَا اقْتَحَمَ الْعَقَبَةَ ۝١١
📖 Itumọ Ẹsẹ 11
Ko si mu akaba igbala gun
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْعَقَبَةُ ۝١٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 12
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je akaba igbala
فَكُّ رَقَبَةٍ ۝١٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 13
(Ohun ni) titu eru sile loko eru
أَوْ إِطْعَامٌ فِي يَوْمٍ ذِي مَسْغَبَةٍ ۝١٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 14
Tabi fifun eniyan ni ounje ni ojo ebi
يَتِيمًا ذَا مَقْرَبَةٍ ۝١٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 15
(O le je) omo-orukan ninu ebi
أَوْ مِسْكِينًا ذَا مَتْرَبَةٍ ۝١٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 16
tabi mekunnu, eni ileele
ثُمَّ كَانَ مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ وَتَوَاصَوْا بِالْمَرْحَمَةِ ۝١٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 17
Leyin naa, ki o wa ninu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won n gbara won niyanju suuru sise, ti won si tun n gbara won niyanju aanu sise
أُولَٰئِكَ أَصْحَابُ الْمَيْمَنَةِ ۝١٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 18
Awon wonyen ni ero owo otun
وَالَّذِينَ كَفَرُوا بِآيَاتِنَا هُمْ أَصْحَابُ الْمَشْأَمَةِ ۝١٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 19
Awon t’o si sai gbagbo ninu awon ayah Wa, awon ni ero owo osi
عَلَيْهِمْ نَارٌ مُّؤْصَدَةٌ ۝٢٠
📖 Itumọ Ẹsẹ 20
A maa ti awon ilekun Ina pa mo won lori patapata
← 89 Al-Balad (90/114) 91 →
Kika Surah Al-Balad ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

90البلد Al-Balad 📚 20 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah Al-Balad — 20 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers