Al-Kahf · 14/110
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Kahf
وَرَبَطْنَا عَلَىٰ قُلُوبِهِمْ إِذْ قَامُوا فَقَالُوا رَبُّنَا رَبُّ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ لَن نَّدْعُوَ مِن دُونِهِ إِلَٰهًا ۖ لَّقَدْ قُلْنَا إِذًا شَطَطًا ۝١٤
Wa rabatnaa `alaa quloo bihim iz qaamoo faqaaloo Rabbunaa Rabbus samaawaati wal ardi lan nad`uwa min dooniheee ilaahal laqad qulnaaa izan shatataa
📖 Ni Yorùbá
A si ki won lokan nigba ti won dide, ti won so pe: "Oluwa wa ni Oluwa awon sanmo ati ile. A o si nii pe olohun kan leyin Re. (Ti a ba pe olohun kan leyin Re) dajudaju a ti pa iro niyen

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 12-16 — Al-Kahf

12ثُمَّ بَعَثْنَاهُمْ لِنَعْلَمَ أَيُّ الْحِزْبَيْنِ أَحْصَىٰ لِمَا لَبِثُوا أَمَدًا
Leyin naa, A gbe won dide nitori ki A le safi han ewo ninu ijo mejeeji l’o mo gbedeke onka odun t’o lo (ninu iho apata naa)
13نَّحْنُ نَقُصُّ عَلَيْكَ نَبَأَهُم بِالْحَقِّ ۚ إِنَّهُمْ فِتْيَةٌ آمَنُوا بِرَبِّهِمْ وَزِدْنَاهُمْ هُدًى
Awa n so iroyin won fun o pelu ododo. Dajudaju odokunrin ni won. Won gbagbo ninu Oluwa won. A si salekun imona fun won
14وَرَبَطْنَا عَلَىٰ قُلُوبِهِمْ إِذْ قَامُوا فَقَالُوا رَبُّنَا رَبُّ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ لَن نَّدْعُوَ مِن دُونِهِ إِلَٰهًا ۖ لَّقَدْ قُلْنَا إِذًا شَطَطًا
A si ki won lokan nigba ti won dide, ti won so pe: "Oluwa wa ni Oluwa awon sanmo ati ile. A o si nii pe olohun kan leyin Re. (Ti a ba pe olohun kan leyin Re) dajudaju a ti pa iro niyen
15هَٰؤُلَاءِ قَوْمُنَا اتَّخَذُوا مِن دُونِهِ آلِهَةً ۖ لَّوْلَا يَأْتُونَ عَلَيْهِم بِسُلْطَانٍ بَيِّنٍ ۖ فَمَنْ أَظْلَمُ مِمَّنِ افْتَرَىٰ عَلَى اللَّهِ كَذِبًا
Awon ijo wa wonyi so awon kan di olohun leyin Allahu. Ki ni ko je ki won mu eri t’o yanju wa nipa won? Nitori naa, ta ni o se abosi ju eni t’o da adapa iro mo Allahu
16وَإِذِ اعْتَزَلْتُمُوهُمْ وَمَا يَعْبُدُونَ إِلَّا اللَّهَ فَأْوُوا إِلَى الْكَهْفِ يَنشُرْ لَكُمْ رَبُّكُم مِّن رَّحْمَتِهِ وَيُهَيِّئْ لَكُم مِّنْ أَمْرِكُم مِّرْفَقًا
(Awon odokunrin naa so funra won pe:) nigba ti e ba yera fun awon ati nnkan ti won n josin fun leyin Allahu, ti e si wa ibugbe sinu iho apata, Oluwa yin yoo te ninu ike Re sile fun yin. O si maa se oro yin ni irorun fun yin
Al-KahfAtokọ Kurani
110Ẹsẹ
MeccanRevelation
14Ẹsẹ

Itumọ — Al-Kahf 14

Surah Al-Kahf Ẹsẹ 14 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : A si ki won lokan nigba ti won dide, ti…

Surah Ẹsẹ 14/110 — Al-Kahf الكهف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Kahf Gbọ, Al-Kahf Itumọ, Al-Kahf mp3, Al-Kahf pdf. Ẹsẹ 12–16. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers