Al-Baqarah · 113/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
وَقَالَتِ الْيَهُودُ لَيْسَتِ النَّصَارَىٰ عَلَىٰ شَيْءٍ وَقَالَتِ النَّصَارَىٰ لَيْسَتِ الْيَهُودُ عَلَىٰ شَيْءٍ وَهُمْ يَتْلُونَ الْكِتَابَ ۗ كَذَٰلِكَ قَالَ الَّذِينَ لَا يَعْلَمُونَ مِثْلَ قَوْلِهِمْ ۚ فَاللَّهُ يَحْكُمُ بَيْنَهُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ فِيمَا كَانُوا فِيهِ يَخْتَلِفُونَ ۝١١٣
Wa qaalatil Yahoodu laisatin Nasaaraa `alaa shai`inw-wa qaalatin Nasaaraaa laisatil Yahoodu `alaa shai`inw`wa hum yatloonal Kitaab; kazaalika qaalal lazeena la ya`lamoona misla qawlihim Yawmal Qiyaamati feemaa kaanoo feehi yakhtalifoon
📖 Ni Yorùbá
Awon yehudi wi pe: “Awon nasara ko ri nnkan kan se (ninu esin).” Awon nasara naa wi pe: “Awon yehudi ko ri nnkan kan se (ninu esin.)” Won si n ke Tira! Bayen ni awon ti ko nimo se so iru oro won (yii). Nitori naa, Allahu a dajo laaarin won ni Ojo Ajinde nipa ohun ti won n yapa enu si

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 111-115 — Surah Al-Baqarah

111وَقَالُوا لَن يَدْخُلَ الْجَنَّةَ إِلَّا مَن كَانَ هُودًا أَوْ نَصَارَىٰ ۗ تِلْكَ أَمَانِيُّهُمْ ۗ قُلْ هَاتُوا بُرْهَانَكُمْ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
Won wi pe: “Eni kan ko nii wo inu Ogba Idera afi eni ti o ba je yehudi tabi nasara.” Iyen ni ife-okan won. So pe: “E mu eri oro yin wa ti e ba je olododo
112بَلَىٰ مَنْ أَسْلَمَ وَجْهَهُ لِلَّهِ وَهُوَ مُحْسِنٌ فَلَهُ أَجْرُهُ عِندَ رَبِّهِ وَلَا خَوْفٌ عَلَيْهِمْ وَلَا هُمْ يَحْزَنُونَ
Bee ko (won ko nii wo inu Ogba Idera afi) eni ti o ba ju ara re sile (ninu ’Islam) fun Allahu, ti o si je oluse rere. Nitori naa, esan (ise) re n be fun un lodo Oluwa re. Ko nii si iberu fun won. Won ko si nii banuje
113وَقَالَتِ الْيَهُودُ لَيْسَتِ النَّصَارَىٰ عَلَىٰ شَيْءٍ وَقَالَتِ النَّصَارَىٰ لَيْسَتِ الْيَهُودُ عَلَىٰ شَيْءٍ وَهُمْ يَتْلُونَ الْكِتَابَ ۗ كَذَٰلِكَ قَالَ الَّذِينَ لَا يَعْلَمُونَ مِثْلَ قَوْلِهِمْ ۚ فَاللَّهُ يَحْكُمُ بَيْنَهُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ فِيمَا كَانُوا فِيهِ يَخْتَلِفُونَ
Awon yehudi wi pe: “Awon nasara ko ri nnkan kan se (ninu esin).” Awon nasara naa wi pe: “Awon yehudi ko ri nnkan kan se (ninu esin.)” Won si n ke Tira! Bayen ni awon ti ko nimo se so iru oro won (yii). Nitori naa, Allahu a dajo laaarin won ni Ojo Ajinde nipa ohun ti won n yapa enu si
114وَمَنْ أَظْلَمُ مِمَّن مَّنَعَ مَسَاجِدَ اللَّهِ أَن يُذْكَرَ فِيهَا اسْمُهُ وَسَعَىٰ فِي خَرَابِهَا ۚ أُولَٰئِكَ مَا كَانَ لَهُمْ أَن يَدْخُلُوهَا إِلَّا خَائِفِينَ ۚ لَهُمْ فِي الدُّنْيَا خِزْيٌ وَلَهُمْ فِي الْآخِرَةِ عَذَابٌ عَظِيمٌ
Ati pe ta l’o sabosi ju eni ti o se awon mosalasi Allahu ni eewo lati seranti oruko Allahu ninu re, ti o tun sise lori iparun awon mosalasi naa? Awon wonyen, ko letoo fun won lati wo inu re ayafi pelu iberu. Abuku n be fun won n’ile aye. Ni orun, iya nla si n be fun won
115وَلِلَّهِ الْمَشْرِقُ وَالْمَغْرِبُ ۚ فَأَيْنَمَا تُوَلُّوا فَثَمَّ وَجْهُ اللَّهِ ۚ إِنَّ اللَّهَ وَاسِعٌ عَلِيمٌ
Ti Allahu ni ibuyo oorun ati ibuwo oorun. Nitori naa, ibikibi ti e ba doju ko ibe yen naa ni ƙiblah Allahu. Dajudaju Allahu ni Olugbaaye, Onimo
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
113Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 113

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 113 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon yehudi wi pe: “Awon nasara ko ri nnkan kan…

Surah Ẹsẹ 113/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 111–115. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers