Al-Baqarah · 133/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
أَمْ كُنتُمْ شُهَدَاءَ إِذْ حَضَرَ يَعْقُوبَ الْمَوْتُ إِذْ قَالَ لِبَنِيهِ مَا تَعْبُدُونَ مِن بَعْدِي قَالُوا نَعْبُدُ إِلَٰهَكَ وَإِلَٰهَ آبَائِكَ إِبْرَاهِيمَ وَإِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ إِلَٰهًا وَاحِدًا وَنَحْنُ لَهُ مُسْلِمُونَ ۝١٣٣
Am kuntum shuhadaaa`a iz hadara Ya`qoobal mawtu iz qaala libaneehi maa ta`budoona mim ba`dee qaaloo na`budu ilaahaka wa ilaaha aabaaa`ika Ibraaheema wa Ismaa`eela wa Ishaaqa Ilaahanw waahidanw wa nahnu lahoo muslimoon
📖 Ni Yorùbá
Tabi eyin je elerii nigba ti iku de ba (Anabi) Ya‘ƙub? Nigba ti o so fun awon omo re pe: “Ki ni eyin yoo maa josin fun leyin (iku) mi?” Won so pe: "Awa yo maa josin fun Olohun re ati Olohun awon baba re, (awon Anabi) ’Ibrohim, ’Ismo‘il ati ’Ishaƙ, Olohun Okan soso. Awa si ni musulumi (ti a juwo juse sile) fun Un

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 131-135 — Al-Baqarah

131إِذْ قَالَ لَهُ رَبُّهُ أَسْلِمْ ۖ قَالَ أَسْلَمْتُ لِرَبِّ الْعَالَمِينَ
(E ranti) nigba ti Oluwa re so fun un pe: “Je musulumi.” O so pe: “Mo je musulumi fun Oluwa gbogbo eda.”
132وَوَصَّىٰ بِهَا إِبْرَاهِيمُ بَنِيهِ وَيَعْقُوبُ يَا بَنِيَّ إِنَّ اللَّهَ اصْطَفَىٰ لَكُمُ الدِّينَ فَلَا تَمُوتُنَّ إِلَّا وَأَنتُم مُّسْلِمُونَ
(Anabi) ’Ibrohim si pa a lase fun awon omo re. (Anabi) Ya‘ƙub naa se bee. (Ikini keji so pe): "Eyin omo mi, dajudaju Allahu yan esin naa fun yin. Nitori naa, e o gbodo ku ayafi ki e je musulumi
133أَمْ كُنتُمْ شُهَدَاءَ إِذْ حَضَرَ يَعْقُوبَ الْمَوْتُ إِذْ قَالَ لِبَنِيهِ مَا تَعْبُدُونَ مِن بَعْدِي قَالُوا نَعْبُدُ إِلَٰهَكَ وَإِلَٰهَ آبَائِكَ إِبْرَاهِيمَ وَإِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ إِلَٰهًا وَاحِدًا وَنَحْنُ لَهُ مُسْلِمُونَ
Tabi eyin je elerii nigba ti iku de ba (Anabi) Ya‘ƙub? Nigba ti o so fun awon omo re pe: “Ki ni eyin yoo maa josin fun leyin (iku) mi?” Won so pe: "Awa yo maa josin fun Olohun re ati Olohun awon baba re, (awon Anabi) ’Ibrohim, ’Ismo‘il ati ’Ishaƙ, Olohun Okan soso. Awa si ni musulumi (ti a juwo juse sile) fun Un
134تِلْكَ أُمَّةٌ قَدْ خَلَتْ ۖ لَهَا مَا كَسَبَتْ وَلَكُم مَّا كَسَبْتُمْ ۖ وَلَا تُسْأَلُونَ عَمَّا كَانُوا يَعْمَلُونَ
Ijo kan niyen ti o ti lo. Tiwon ni ohun ti won se nise. Tiyin ni ohun ti e se nise. Won ko si nii bi yin leere nipa ohun ti won n se nise
135وَقَالُوا كُونُوا هُودًا أَوْ نَصَارَىٰ تَهْتَدُوا ۗ قُلْ بَلْ مِلَّةَ إِبْرَاهِيمَ حَنِيفًا ۖ وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
Won wi pe: “E je yehudi tabi nasara ki e mona.” So pe: "Rara, esin (Anabi) ’Ibrohim (lesin), oluduro-deede, ko si si ninu awon osebo
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
133Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 133

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 133 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Tabi eyin je elerii nigba ti iku de ba (Anabi)…

Surah Ẹsẹ 133/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 131–135. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers