Taha · 40/135
Itumọ Aṣẹ ohun — Taha
إِذْ تَمْشِي أُخْتُكَ فَتَقُولُ هَلْ أَدُلُّكُمْ عَلَىٰ مَن يَكْفُلُهُ ۖ فَرَجَعْنَاكَ إِلَىٰ أُمِّكَ كَيْ تَقَرَّ عَيْنُهَا وَلَا تَحْزَنَ ۚ وَقَتَلْتَ نَفْسًا فَنَجَّيْنَاكَ مِنَ الْغَمِّ وَفَتَنَّاكَ فُتُونًا ۚ فَلَبِثْتَ سِنِينَ فِي أَهْلِ مَدْيَنَ ثُمَّ جِئْتَ عَلَىٰ قَدَرٍ يَا مُوسَىٰ ۝٤٠
Iz tamsheee ukhtuka fataqoolu hal adullukum `alaa mai yakfuluhoo faraja `naaka ilaaa ummika kai taqarra `ainuhaa wa laa tahzan; wa qatalta nafsan fanajjainaaka minal ghammi wa fatannaaka futoonaa; falabista sineena feee ahli Madyana summa ji`ta `alaa qadariny yaa Moosa
📖 Ni Yorùbá
(Ranti) nigba ti arabinrin re n rin lo, o si so pe: “Se ki ng juwe eni ti o maa gba a to (fun yin)?” A si da o pada sodo iya re nitori ki o le ni itutu oju, ko si nii banuje. Ati pe o pa emi eni kan. A si mu o kuro ninu ibanuje. A tun mu awon adanwo kan ba o. O tun lo awon odun kan lodo awon ara Modyan. Leyin naa, o de (ni akoko) ti o ti wa ninu kadara, Musa
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 38-42 — Taha

38إِذْ أَوْحَيْنَا إِلَىٰ أُمِّكَ مَا يُوحَىٰ
(Ranti) nigba ti A sipaya ohun ti A sipaya fun iya re
39أَنِ اقْذِفِيهِ فِي التَّابُوتِ فَاقْذِفِيهِ فِي الْيَمِّ فَلْيُلْقِهِ الْيَمُّ بِالسَّاحِلِ يَأْخُذْهُ عَدُوٌّ لِّي وَعَدُوٌّ لَّهُ ۚ وَأَلْقَيْتُ عَلَيْكَ مَحَبَّةً مِّنِّي وَلِتُصْنَعَ عَلَىٰ عَيْنِي
pe: “Ju Musa sinu apoti. Ki o si gbe e ju sinu agbami odo. Odo yo si gbe e ju si eti odo. Ota Mi ati ota re si maa gbe e.” Mo si da ife lati odo Mi bo o nitori ki won le toju re loju Mi.”
40إِذْ تَمْشِي أُخْتُكَ فَتَقُولُ هَلْ أَدُلُّكُمْ عَلَىٰ مَن يَكْفُلُهُ ۖ فَرَجَعْنَاكَ إِلَىٰ أُمِّكَ كَيْ تَقَرَّ عَيْنُهَا وَلَا تَحْزَنَ ۚ وَقَتَلْتَ نَفْسًا فَنَجَّيْنَاكَ مِنَ الْغَمِّ وَفَتَنَّاكَ فُتُونًا ۚ فَلَبِثْتَ سِنِينَ فِي أَهْلِ مَدْيَنَ ثُمَّ جِئْتَ عَلَىٰ قَدَرٍ يَا مُوسَىٰ
(Ranti) nigba ti arabinrin re n rin lo, o si so pe: “Se ki ng juwe eni ti o maa gba a to (fun yin)?” A si da o pada sodo iya re nitori ki o le ni itutu oju, ko si nii banuje. Ati pe o pa emi eni kan. A si mu o kuro ninu ibanuje. A tun mu awon adanwo kan ba o. O tun lo awon odun kan lodo awon ara Modyan. Leyin naa, o de (ni akoko) ti o ti wa ninu kadara, Musa
41وَاصْطَنَعْتُكَ لِنَفْسِي
Mo si sa o lesa fun (ise) Mi
42اذْهَبْ أَنتَ وَأَخُوكَ بِآيَاتِي وَلَا تَنِيَا فِي ذِكْرِي
Lo, iwo ati arakunrin re, pelu awon ami (ise iyanu) Mi. Ki e si ma se kole ninu iranti Mi
TahaAtokọ Kurani
135Ẹsẹ
MeccanRevelation
40Ẹsẹ

Itumọ — Taha 40

Surah Taha Ẹsẹ 40 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (Ranti) nigba ti arabinrin re n rin lo, o si…

Surah Ẹsẹ 40/135 — Taha طه (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Taha Gbọ, Taha Itumọ, Taha mp3, Taha pdf. Ẹsẹ 38–42. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers