"صَدَقْنَاهُمُ الْوَعْدَ": ṣe ìmúṣẹ́ ìlérí fún wọn.
"أَنجَيْنَاهُمْ": gbà wọ́n là.
"الْمُسْرِفِينَ": àwọn tí wọ́n tayọ ààlà ní ọ̀nà àìgbàgbọ́ àti ẹ̀ṣẹ̀.
Ìtumọ̀ āyà:
Lẹ́yìn náà, Allāh mú ìlérí tí Ó ṣe fún àwọn ànábì àti àwọn tí wọ́n gbà wọ́n gbọ́ ṣẹ, Ó gbà wọ́n là pẹ̀lú àwọn tí Ó fẹ́ láti inú àwọn onígbàgbọ́, Ó sì pa àwọn tí wọ́n tayọ ààlà nínú àìgbàgbọ́ wọn àti ìwà ẹ̀ṣẹ̀ wọn run. Èyí fi hàn pé ìlérí Allāh kì í yẹ̀, àti pé ìgbàlà wà fún àwọn tí wọ́n gbà Á gbọ́, nígbà tí ìparun ń bẹ fún àwọn aláìgbàgbọ́ tí wọ́n ń tẹ̀síwájú nínú ìṣìnà.
Àwọn ẹ̀kọ́ tí ó ń sọ ènìyàn ní ìfẹ́ sí Islām àti Al-Qur'ān:
Allāh kì í ṣe aláìṣòótọ́ nínú ìlérí Rẹ̀; ẹni tí ó bá gbà Á gbọ́ yóò rí ìgbàlà.
Àwọn ànábì àti àwọn tí wọ́n tẹ̀lé wọn jẹ́ àpẹẹrẹ ìrètí àti ìdánilójú fún gbogbo onígbàgbọ́.
Ìwà àṣejù nínú àìgbàgbọ́ àti ẹ̀ṣẹ̀ ń yọrí sí ìparun; ṣùgbọ́n àánú Allāh wà fún ẹni tí ó bá ronú pìwà dà.
Al-Qur'ān jẹ́ ìtọ́ni tí ó ń fi ìfẹ́ Allāh àti ìdájọ́ Rẹ̀ hàn, kí ènìyàn lè yàn ọ̀nà ìgbàlà.
A ko si se won ni abara ti ko nii jeun. Won ko si je olusegbere (nile aye). abara ni ki i se olohun. Allahu awon oku ko le gbo oro kan kan mo lati odo awon alaaye ni ibamu si surah an-Naml; 27:80 surah ar-Rum; 30:52 ati surah Fatir; 35:22. Anabi wa Muhammad (sollalahu alayhi wa sallam) si pada di oku ti won bo mo inu saree ninu ilu Modinah Onimoole ni ibamu si surah az-Zumor; 39:30. Ko si si ayah taara kan ninu al-Ƙur’an ti o yo Anabi wa Muhammad (sollalahu alayhi wa sallam) sile ninu awon oku ti ko le gbo oro kan kan mo lati odo awon alaaye. Amo hadith t’o fese rinle wa ti o n fi rinle pe “Ko si eni kan ti o maa salamo si mi afi ki Allahu da emi mi pada si mi lara titi mo maa fi da salamo naa pada fun un.” Abu Daud l’o gba a wa labe akole: bab ziyaratul-ƙubur. Seek al-Baniy so pe “hadith naa dara”. Hadith yii tun wa ninu musnad ’Ahmad ati sunan Baehaƙiy. Ojise Allahu (sollalahu alayhi wa sallam) so pe “Dajudaju ojo Jum‘ah wa ninu awon ojo yin t’o loore julo; Won seda Anabi Adam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ninu re ni isele t’o tayo oye wa amo ti o tenu Anabi wa Muhammad olododo (sollalahu alayhi wa sallam) jade ti o si dari yin pelu ohun ti n be lodo yin.” Eni kan ninu awon t’o gba hadith yii wa so pe “Ki ni itumo “ti o si dari yin pelu ohun ti n be lodo yin”? Tabi ki ni itumo “ti ohun ti o maa fi dari yin si maa wa lati odo yin?” Ibnu Abi Thanb si fesi pe
SurahQuran.com was founded as a humble effort to serve the Noble Book and the pure Sunnah, to invite people to Allah, and to make the religious sciences accessible according to the methodology of the Quran and Sunnah. We praise and thank Allah for His grace, and we ask Him to accept our work and make it sincere for His noble Face.