Al-Furqan · 31/77
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Furqan
وَكَذَٰلِكَ جَعَلْنَا لِكُلِّ نَبِيٍّ عَدُوًّا مِّنَ الْمُجْرِمِينَ ۗ وَكَفَىٰ بِرَبِّكَ هَادِيًا وَنَصِيرًا ٣١
Transliteration
Wa kazaalika ja`alnaa likulli Nabiyyin `aduwwam minal mujrimeen; wa kafaa bi Rabbika haadiyanw wa naseeraa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Bayen ni A se awon kan ninu awon elese ni ota fun Anabi kookan. Oluwa re si to ni Afinimona ati Alaranse
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 29-33 — Al-Furqan
29لَّقَدْ أَضَلَّنِي عَنِ الذِّكْرِ بَعْدَ إِذْ جَاءَنِي ۗ وَكَانَ الشَّيْطَانُ لِلْإِنسَانِ خَذُولًا
Dajudaju o ti si mi lona kuro nibi Iranti leyin ti o de ba mi. Dajudaju Esu n je adani-dasoro fun omoniyan
30وَقَالَ الرَّسُولُ يَا رَبِّ إِنَّ قَوْمِي اتَّخَذُوا هَٰذَا الْقُرْآنَ مَهْجُورًا
Ojise naa so pe: “Oluwa mi dajudaju awon eniyan mi ti pa al-Ƙur’an yii ti.”
31وَكَذَٰلِكَ جَعَلْنَا لِكُلِّ نَبِيٍّ عَدُوًّا مِّنَ الْمُجْرِمِينَ ۗ وَكَفَىٰ بِرَبِّكَ هَادِيًا وَنَصِيرًا
Bayen ni A se awon kan ninu awon elese ni ota fun Anabi kookan. Oluwa re si to ni Afinimona ati Alaranse
32وَقَالَ الَّذِينَ كَفَرُوا لَوْلَا نُزِّلَ عَلَيْهِ الْقُرْآنُ جُمْلَةً وَاحِدَةً ۚ كَذَٰلِكَ لِنُثَبِّتَ بِهِ فُؤَادَكَ ۖ وَرَتَّلْنَاهُ تَرْتِيلًا
Awon t’o sai gbagbo wi pe: “Won ko se so al-Ƙur’an kale fun un ni apapo ni ee kan naa?” (A so o kale diedie) bayen nitori ki A le fi rinle sinu okan re. A si ke e fun o diedie
33وَلَا يَأْتُونَكَ بِمَثَلٍ إِلَّا جِئْنَاكَ بِالْحَقِّ وَأَحْسَنَ تَفْسِيرًا
Won ko nii mu apeere kan wa fun o (bi ibeere lati fi tako o) afi ki A mu ododo (iyen, al-ƙur’an) ati alaye t’o dara julo wa fun o (lori re)
Al-FurqanAtokọ Kurani
77Ẹsẹ
MeccanRevelation
31Ẹsẹ
Itumọ — Al-Furqan 31
Surah Al-Furqan Ẹsẹ 31 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Bayen ni A se awon kan ninu awon elese ni…Surah Ẹsẹ 31/77 — Al-Furqan الفرقان (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Furqan Gbọ, Al-Furqan Itumọ, Al-Furqan mp3, Al-Furqan pdf. Ẹsẹ 29–33. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








