Ash-Shu'ara · 192/227
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ash-Shu'ara
وَإِنَّهُ لَتَنزِيلُ رَبِّ الْعَالَمِينَ ۝١٩٢
Wa innahoo latanzeelu Rabbil `aalameen
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju al-Ƙur’an, won so o kale ni lati odo Oluwa gbogbo eda

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 190-194 — Surah Ash-Shu'ara

190إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَآيَةً ۖ وَمَا كَانَ أَكْثَرُهُم مُّؤْمِنِينَ
Dajudaju ami wa ninu iyen. Opolopo won ni ko si je onigbagbo ododo
191وَإِنَّ رَبَّكَ لَهُوَ الْعَزِيزُ الرَّحِيمُ
Dajudaju Oluwa re, Oun ma ni Alagbara, Asake-orun
192وَإِنَّهُ لَتَنزِيلُ رَبِّ الْعَالَمِينَ
Dajudaju al-Ƙur’an, won so o kale ni lati odo Oluwa gbogbo eda
193نَزَلَ بِهِ الرُّوحُ الْأَمِينُ
Molaika Jibril, olufokantan l’o so o kale
194عَلَىٰ قَلْبِكَ لِتَكُونَ مِنَ الْمُنذِرِينَ
sinu okan re nitori ki o le wa ninu awon olukilo
Ash-Shu'araAtokọ Kurani
227Ẹsẹ
MeccanRevelation
192Ẹsẹ

Itumọ — Ash-Shu'ara 192

Surah Ash-Shu'ara Ẹsẹ 192 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju al-Ƙur’an, won so o kale ni lati odo Oluwa…

Surah Ẹsẹ 192/227 — Surah Ash-Shu'ara الشعراء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ash-Shu'ara Gbọ, Surah Ash-Shu'ara Itumọ, Surah Ash-Shu'ara mp3, Surah Ash-Shu'ara pdf. Ẹsẹ 190–194. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers