Aal-Imran · 71/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَلْبِسُونَ الْحَقَّ بِالْبَاطِلِ وَتَكْتُمُونَ الْحَقَّ وَأَنتُمْ تَعْلَمُونَ ۝٧١
Yaaa Ahalal Kitaabi lima talbisoonal haqqa bilbaatili wa taktumoonal haqqa wa antum ta`lamoon
📖 Ni Yorùbá
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi da iro po mo ododo, e si n fi ododo pamo nigba ti eyin mo (ododo)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 69-73 — Surah Aal-Imran

69وَدَّت طَّائِفَةٌ مِّنْ أَهْلِ الْكِتَابِ لَوْ يُضِلُّونَكُمْ وَمَا يُضِلُّونَ إِلَّا أَنفُسَهُمْ وَمَا يَشْعُرُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab fe lati si yin lona. Won ko le si enikeni lona afi ara won, won ko si fura
70يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَأَنتُمْ تَشْهَدُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, e si n jerii (si ododo re)
71يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَلْبِسُونَ الْحَقَّ بِالْبَاطِلِ وَتَكْتُمُونَ الْحَقَّ وَأَنتُمْ تَعْلَمُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi da iro po mo ododo, e si n fi ododo pamo nigba ti eyin mo (ododo)
72وَقَالَت طَّائِفَةٌ مِّنْ أَهْلِ الْكِتَابِ آمِنُوا بِالَّذِي أُنزِلَ عَلَى الَّذِينَ آمَنُوا وَجْهَ النَّهَارِ وَاكْفُرُوا آخِرَهُ لَعَلَّهُمْ يَرْجِعُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab wi pe: “E lo gbagbo ninu ohun ti Won sokale fun awon t’o gbagbo ni ododo nibere ojo, ki e si tako o nipari re, boya awon musulumi (kan) maa seri pada (seyin ninu esin ’Islam)
73وَلَا تُؤْمِنُوا إِلَّا لِمَن تَبِعَ دِينَكُمْ قُلْ إِنَّ الْهُدَىٰ هُدَى اللَّهِ أَن يُؤْتَىٰ أَحَدٌ مِّثْلَ مَا أُوتِيتُمْ أَوْ يُحَاجُّوكُمْ عِندَ رَبِّكُمْ ۗ قُلْ إِنَّ الْفَضْلَ بِيَدِ اللَّهِ يُؤْتِيهِ مَن يَشَاءُ ۗ وَاللَّهُ وَاسِعٌ عَلِيمٌ
(Won tun wi pe:) “E ma gbagbo ayafi eni ti o ba tele esin yin.” So pe: “Dajudaju imona (’Islam) ni imona ti Allahu.” (Won tun wi pe:) “(E ma gbagbo) pe won fun eni kan ni iru ohun ti Won fun yin tabi pe won yoo tako yin (ti won yo si jare yin) lodo Oluwa yin.” So pe: “Dajudaju oore ajulo wa ni owo Allahu. O n fun eni ti O ba fe. Allahu ni Olugbaaye, Onimo.”
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
71Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 71

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 71 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi da iro…

Surah Ẹsẹ 71/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 69–73. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers