Wa maa anta bihaadil `umyi `an dalaalatihim in tusmi`u illaa mai yuminu bi aayaatinaa fahum muslimoon
📖 Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Iwo ko l’o maa fi ona mo awon afoju nibi isina won. Ko si eni ti o maa mu gbo oro afi eni ti o ba gba awon ayah Wa gbo. Awon si ni (musulumi) olujupa-juse-sile fun Allahu. Allahu (subhanahu wa ta’ala) l’O n sise iyanu. Ko si si Anabi tabi Ojise Olohun kan ti Allahu ko fun ni ise iyanu kan tabi omiran se ni ibamu si igba eni kookan won. Bee si ni eyikeyii ise iyanu ti o ba towo Anabi tabi Ojise kan waye ko so Anabi tabi Ojise naa di oluwa ati olugbala. Allahu nikan soso ni Oluwa ati Olugbala aye ati orun. Nitori naa fun alekun lori awon ise iyanu Anabi ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ti Allahu ba fe. Allahu si ni Alagbara lori gbogbo nnkan. Amo awon kristieni gege bi isesi won bi o se n wu u to ati bi o se n jerankan to ni pe ki gbogbo awon eniyan re gbagbo ninu Allahu. Amo won ko gbagbo
"مُسْلِمُونَ": àwọn tí wọ́n jẹ́ ọlọ́kàn tẹ̀ríba fún Allāh.
Ìtumọ̀ āyà:
Ìwọ kì í ṣe ẹni tí yóò tọ́ àwọn afọ́jú ẹ̀mí lọ́nà kúrò nínú ìṣìnà wọn, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò lè mú kí ẹnikẹ́ni gbọ́ ọ̀rọ̀ tí yóò fi àǹfààní jáde àyàfi ẹni tí ó gbà àwọn āyà Wa gbọ́. Àwọn wọ̀nyí ni yóò gbọ́, wọ́n sì máa tẹ̀ríba fún Allāh, wọ́n máa ṣe ìtẹ̀ríba fún àṣẹ Rẹ̀, wọ́n sì máa jẹ́ olùgbọràn.
Àwọn ẹ̀kọ́ tí ó ń sọ àwọn ènìyàn ní ìfẹ́ sí ìsìnàmí àti Qur'ān:
Allāh ni ó ń tọ́nà ẹni tí ó fẹ́, kì í ṣe ọwọ́ ènìyàn.
Ẹni tí ó bá gbà àwọn āyà Allāh gbọ́ ni yóò fi ọ̀rọ̀ mọ̀, yóò sì tẹ̀ríba fún Allāh.
Ìtẹ̀ríba àti ìgbọràn fún Allāh ni kókó ìsìnàmí tòótọ́.
Àwọn tí wọ́n bá gbà á gbọ́ ni yóò ní àǹfààní nínú ọ̀rọ̀ náà, wọ́n sì máa jẹ́ ẹni ìbùkún.
Ó yẹ kí a máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Allāh tí ó jẹ́ kí a gbọ́ ọ̀rọ̀ Rẹ̀, kí a sì máa tẹ̀lé e.
Iwo ko l’o maa fi ona mo awon afoju nibi isina won. Ko si eni ti o maa mu gbo oro afi eni ti o ba gba awon ayah Wa gbo. Awon si ni (musulumi) olujupa-juse-sile fun Allahu. Allahu (subhanahu wa ta’ala) l’O n sise iyanu. Ko si si Anabi tabi Ojise Olohun kan ti Allahu ko fun ni ise iyanu kan tabi omiran se ni ibamu si igba eni kookan won. Bee si ni eyikeyii ise iyanu ti o ba towo Anabi tabi Ojise kan waye ko so Anabi tabi Ojise naa di oluwa ati olugbala. Allahu nikan soso ni Oluwa ati Olugbala aye ati orun. Nitori naa fun alekun lori awon ise iyanu Anabi ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ti Allahu ba fe. Allahu si ni Alagbara lori gbogbo nnkan. Amo awon kristieni gege bi isesi won bi o se n wu u to ati bi o se n jerankan to ni pe ki gbogbo awon eniyan re gbagbo ninu Allahu. Amo won ko gbagbo
Iwo ko l’o maa fi ona mo awon afoju nibi isina won. Ko si eni ti o maa mu gbo oro afi eni ti o ba gba awon ayah Wa gbo. Awon si ni (musulumi) olujupa-juse-sile fun Allahu. Allahu (subhanahu wa ta’ala) l’O n sise iyanu. Ko si si Anabi tabi Ojise Olohun kan ti Allahu ko fun ni ise iyanu kan tabi omiran se ni ibamu si igba eni kookan won. Bee si ni eyikeyii ise iyanu ti o ba towo Anabi tabi Ojise kan waye ko so Anabi tabi Ojise naa di oluwa ati olugbala. Allahu nikan soso ni Oluwa ati Olugbala aye ati orun. Nitori naa fun alekun lori awon ise iyanu Anabi ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ti Allahu ba fe. Allahu si ni Alagbara lori gbogbo nnkan. Amo awon kristieni gege bi isesi won bi o se n wu u to ati bi o se n jerankan to ni pe ki gbogbo awon eniyan re gbagbo ninu Allahu. Amo won ko gbagbo
Allahu, Eni ti O seda yin lati (ara nnkan) lile, leyin naa, leyin lile O fun (yin ni) agbara, leyin naa, leyin agbara, O tun fi lile ati ogbo (si yin lara). O n da ohunkohun ti O ba fe. Oun si ni Onimo, Alagbara
Ati pe ni ojo ti Akoko naa ba sele (iyen, ojo Ajinde), awon elese yoo maa bura pe awon ko gbe (ile aye) ju akoko kan lo.” Bayen ni won se maa n f’iro tanra won je
SurahQuran.com was founded as a humble effort to serve the Noble Book and the pure Sunnah, to invite people to Allah, and to make the religious sciences accessible according to the methodology of the Quran and Sunnah. We praise and thank Allah for His grace, and we ask Him to accept our work and make it sincere for His noble Face.