Muhammad · 38/38
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Muhammad
هَا أَنتُمْ هَٰؤُلَاءِ تُدْعَوْنَ لِتُنفِقُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ فَمِنكُم مَّن يَبْخَلُ ۖ وَمَن يَبْخَلْ فَإِنَّمَا يَبْخَلُ عَن نَّفْسِهِ ۚ وَاللَّهُ الْغَنِيُّ وَأَنتُمُ الْفُقَرَاءُ ۚ وَإِن تَتَوَلَّوْا يَسْتَبْدِلْ قَوْمًا غَيْرَكُمْ ثُمَّ لَا يَكُونُوا أَمْثَالَكُم ۝٣٨
haaa antum haaa`ulaaa`i tud`awna litunfiqoo fee sabeelillaahi faminkum many yabkhalu wa many yabkhal fa innamaa yabkhalu `an nafsih; wallaahu Ghaniyyu wa antumul fuqaraaa`; wa in tatwal law yastabdil qawman ghairakum summa laa yakoonooo amsaalakum
📖 Ni Yorùbá
Eyin naa ma niwonyi ti won n pe lati nawo fun esin Allahu. Sugbon eni t’o n sahun wa ninu yin. Enikeni ti o ba sahun, o se e fun emi ara re. Allahu ni Oloro. Eyin si ni alaini. Ti e ba gbunri, (Allahu) maa fi ijo miiran paaro yin. Leyin naa, won ko si nii da bi iru yin

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 36-38 — Surah Muhammad

36إِنَّمَا الْحَيَاةُ الدُّنْيَا لَعِبٌ وَلَهْوٌ ۚ وَإِن تُؤْمِنُوا وَتَتَّقُوا يُؤْتِكُمْ أُجُورَكُمْ وَلَا يَسْأَلْكُمْ أَمْوَالَكُمْ
Ere ati iranu ni isemi aye. (Amo) ti e ba gbagbo (ninu Allahu), ti e si beru (Re), O maa fun yin ni awon esan yin. Ko si nii beere awon dukia yin (pe ki e fi gbogbo re yo Zakah)
37إِن يَسْأَلْكُمُوهَا فَيُحْفِكُمْ تَبْخَلُوا وَيُخْرِجْ أَضْغَانَكُمْ
Ti (Allahu) ba beere re ni owo yin (pe ki e fi gbogbo re yo Zakah), ti O si wonkoko mo yin, e maa sahun. O si maa mu arun okan yin jade (asiri yin yo si tu sita)
38هَا أَنتُمْ هَٰؤُلَاءِ تُدْعَوْنَ لِتُنفِقُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ فَمِنكُم مَّن يَبْخَلُ ۖ وَمَن يَبْخَلْ فَإِنَّمَا يَبْخَلُ عَن نَّفْسِهِ ۚ وَاللَّهُ الْغَنِيُّ وَأَنتُمُ الْفُقَرَاءُ ۚ وَإِن تَتَوَلَّوْا يَسْتَبْدِلْ قَوْمًا غَيْرَكُمْ ثُمَّ لَا يَكُونُوا أَمْثَالَكُم
Eyin naa ma niwonyi ti won n pe lati nawo fun esin Allahu. Sugbon eni t’o n sahun wa ninu yin. Enikeni ti o ba sahun, o se e fun emi ara re. Allahu ni Oloro. Eyin si ni alaini. Ti e ba gbunri, (Allahu) maa fi ijo miiran paaro yin. Leyin naa, won ko si nii da bi iru yin
MuhammadAtokọ Kurani
38Ẹsẹ
MedinanRevelation
38Ẹsẹ

Itumọ — Muhammad 38

Surah Muhammad Ẹsẹ 38 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eyin naa ma niwonyi ti won n pe lati nawo…

Surah Ẹsẹ 38/38 — Surah Muhammad محمد (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Muhammad Gbọ, Surah Muhammad Itumọ, Surah Muhammad mp3, Surah Muhammad pdf. Ẹsẹ 36–38. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers