As-Saff · 13/14
Itumọ Aṣẹ ohun — As-Saff
وَأُخْرَىٰ تُحِبُّونَهَا ۖ نَصْرٌ مِّنَ اللَّهِ وَفَتْحٌ قَرِيبٌ ۗ وَبَشِّرِ الْمُؤْمِنِينَ ١٣
Transliteration
Wa ukhraa tuhibboonahaa nasrum minal laahi wa fat hun qaree; wa bashshiril mu `mineen
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse lati odo Allahu ati isegun t’o sunmo. Ki o si fun awon onigbagbo ododo ni iro idunnu
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 11-14 — As-Saff
11تُؤْمِنُونَ بِاللَّهِ وَرَسُولِهِ وَتُجَاهِدُونَ فِي سَبِيلِ اللَّهِ بِأَمْوَالِكُمْ وَأَنفُسِكُمْ ۚ ذَٰلِكُمْ خَيْرٌ لَّكُمْ إِن كُنتُمْ تَعْلَمُونَ
E gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, e jagun soju ona (esin) Allahu pelu awon dukia yin ati emi yin. Iyen loore julo fun yin ti e ba mo
12يَغْفِرْ لَكُمْ ذُنُوبَكُمْ وَيُدْخِلْكُمْ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ وَمَسَاكِنَ طَيِّبَةً فِي جَنَّاتِ عَدْنٍ ۚ ذَٰلِكَ الْفَوْزُ الْعَظِيمُ
(Allahu) maa fori ese yin jin yin. O si maa mu yin wo inu awon Ogba Idera, ti awon odo n san ni isale re ati awon ibugbe t’o dara ninu awon Ogba Idera gbere. Iyen ni erenje nla
13وَأُخْرَىٰ تُحِبُّونَهَا ۖ نَصْرٌ مِّنَ اللَّهِ وَفَتْحٌ قَرِيبٌ ۗ وَبَشِّرِ الْمُؤْمِنِينَ
Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse lati odo Allahu ati isegun t’o sunmo. Ki o si fun awon onigbagbo ododo ni iro idunnu
14يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا كُونُوا أَنصَارَ اللَّهِ كَمَا قَالَ عِيسَى ابْنُ مَرْيَمَ لِلْحَوَارِيِّينَ مَنْ أَنصَارِي إِلَى اللَّهِ ۖ قَالَ الْحَوَارِيُّونَ نَحْنُ أَنصَارُ اللَّهِ ۖ فَآمَنَت طَّائِفَةٌ مِّن بَنِي إِسْرَائِيلَ وَكَفَرَت طَّائِفَةٌ ۖ فَأَيَّدْنَا الَّذِينَ آمَنُوا عَلَىٰ عَدُوِّهِمْ فَأَصْبَحُوا ظَاهِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e je alaranse fun esin Allahu gege bi (Anabi) ‘Isa omo Moryam se so fun awon omoleyin re pe: "Ta ni o maa se iranlowo fun mi nipa esin Allahu?" Awon omoleyin re so pe: "Awa ni alaranse fun esin Allahu." Igun kan ninu awon omo ’Isro’il gba a gbo ni ododo nigba naa, igun kan si sai gbagbo ninu re. A si fun awon t’o gbagbo lagbara lori awon ota won; won si di olubori
As-SaffAtokọ Kurani
14Ẹsẹ
MedinanRevelation
13Ẹsẹ
Itumọ — As-Saff 13
Surah As-Saff Ẹsẹ 13 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse…Surah Ẹsẹ 13/14 — As-Saff الصف (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: As-Saff Gbọ, As-Saff Itumọ, As-Saff mp3, As-Saff pdf. Ẹsẹ 11–14. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








