Al-Jumu'ah · 5/11
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Jumu'ah
مَثَلُ الَّذِينَ حُمِّلُوا التَّوْرَاةَ ثُمَّ لَمْ يَحْمِلُوهَا كَمَثَلِ الْحِمَارِ يَحْمِلُ أَسْفَارًا ۚ بِئْسَ مَثَلُ الْقَوْمِ الَّذِينَ كَذَّبُوا بِآيَاتِ اللَّهِ ۚ وَاللَّهُ لَا يَهْدِي الْقَوْمَ الظَّالِمِينَ ۝٥
Masalul lazeena hum milut tawraata summa lam yahmiloonhaa kamasalil himaari yah milu asfaaraa; bi`sa masalul qawmil lazeena kaazzaboo bi aayaatil laah; wallaahu laa yahdil qawmazzaalimeen
📖 Ni Yorùbá
Apejuwe ijo ti A fun ni Taorah, leyin naa ti won ko tele e, o da bi apejuwe ketekete ti o ru eru awon tira. Aburu ni apejuwe awon t’o pe awon ayah Allahu niro. Allahu ko si nii fi ona mo ijo alabosi
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 3-7 — Al-Jumu'ah

3وَآخَرِينَ مِنْهُمْ لَمَّا يَلْحَقُوا بِهِمْ ۚ وَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
(Ise jije re tun wa fun) awon miiran ti won maa wa ninu awon (omoleyin re), amo ti won ko ti i rin kan won. (Allahu) Oun ni Alagbara, Ologbon
4ذَٰلِكَ فَضْلُ اللَّهِ يُؤْتِيهِ مَن يَشَاءُ ۚ وَاللَّهُ ذُو الْفَضْلِ الْعَظِيمِ
Iyen ni oore ajulo Allahu. O n fun eni ti O ba fe. Allahu si ni Oloore-ajulo nla
5مَثَلُ الَّذِينَ حُمِّلُوا التَّوْرَاةَ ثُمَّ لَمْ يَحْمِلُوهَا كَمَثَلِ الْحِمَارِ يَحْمِلُ أَسْفَارًا ۚ بِئْسَ مَثَلُ الْقَوْمِ الَّذِينَ كَذَّبُوا بِآيَاتِ اللَّهِ ۚ وَاللَّهُ لَا يَهْدِي الْقَوْمَ الظَّالِمِينَ
Apejuwe ijo ti A fun ni Taorah, leyin naa ti won ko tele e, o da bi apejuwe ketekete ti o ru eru awon tira. Aburu ni apejuwe awon t’o pe awon ayah Allahu niro. Allahu ko si nii fi ona mo ijo alabosi
6قُلْ يَا أَيُّهَا الَّذِينَ هَادُوا إِن زَعَمْتُمْ أَنَّكُمْ أَوْلِيَاءُ لِلَّهِ مِن دُونِ النَّاسِ فَتَمَنَّوُا الْمَوْتَ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
So pe: "Eyin yehudi, ti e ba lero pe dajudaju eyin ni ore Allahu dipo awon eniyan (yooku), e toro iku nigba naa ti e ba je olododo
7وَلَا يَتَمَنَّوْنَهُ أَبَدًا بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيهِمْ ۚ وَاللَّهُ عَلِيمٌ بِالظَّالِمِينَ
Won ko nii toro re laelae nitori ohun ti owo won ti ti siwaju. Allahu si ni Onimo nipa awon alabosi
Al-Jumu'ahAtokọ Kurani
11Ẹsẹ
MedinanRevelation
5Ẹsẹ

Itumọ — Al-Jumu'ah 5

Surah Al-Jumu'ah Ẹsẹ 5 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Apejuwe ijo ti A fun ni Taorah, leyin naa ti…

Surah Ẹsẹ 5/11 — Al-Jumu'ah الجمعة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Jumu'ah Gbọ, Al-Jumu'ah Itumọ, Al-Jumu'ah mp3, Al-Jumu'ah pdf. Ẹsẹ 3–7. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers