Surah Al-Layl ni Arabic ati Yorùbá
Ka Surah Al-Layl pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (21 Ẹsẹ — مكية). Al-Layl Gbọ, Al-Layl Itumọ, Al-Layl mp3, Al-Layl pdf.Ka ati Gbọ Surah Al-Layl
🎧 Ẹsẹ
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
—
x1
وَأَمَّا مَن بَخِلَ وَاسْتَغْنَىٰ ٨
📖 Itumọ
Ẹsẹ 8
Ni ti eni ti o ba yahun, ti o si ri ara re leni t’o roro tayo esan orun
وَمَا يُغْنِي عَنْهُ مَالُهُ إِذَا تَرَدَّىٰ ١١
📖 Itumọ
Ẹsẹ 11
Dukia re ko si nii ro o loro nigba ti o ba ja bo (sinu Ina)
فَأَنذَرْتُكُمْ نَارًا تَلَظَّىٰ ١٤
📖 Itumọ
Ẹsẹ 14
Nitori naa, Mo ti fi Ina elejo fofo kilo fun yin
الَّذِي يُؤْتِي مَالَهُ يَتَزَكَّىٰ ١٨
📖 Itumọ
Ẹsẹ 18
eni t’o n fi dukia re tore, ti o n safomo (re)
وَمَا لِأَحَدٍ عِندَهُ مِن نِّعْمَةٍ تُجْزَىٰ ١٩
📖 Itumọ
Ẹsẹ 19
Ko si si oore idera kan ti (o ni lokan) lati gba ni esan ni odo enikeni
إِلَّا ابْتِغَاءَ وَجْهِ رَبِّهِ الْأَعْلَىٰ ٢٠
📖 Itumọ
Ẹsẹ 20
bi ko se pe lati fi wa oju rere Oluwa re, Eni Giga julo
Kika Surah Al-Layl ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers

