Al-Baqarah · 136/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
قُولُوا آمَنَّا بِاللَّهِ وَمَا أُنزِلَ إِلَيْنَا وَمَا أُنزِلَ إِلَىٰ إِبْرَاهِيمَ وَإِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ وَيَعْقُوبَ وَالْأَسْبَاطِ وَمَا أُوتِيَ مُوسَىٰ وَعِيسَىٰ وَمَا أُوتِيَ النَّبِيُّونَ مِن رَّبِّهِمْ لَا نُفَرِّقُ بَيْنَ أَحَدٍ مِّنْهُمْ وَنَحْنُ لَهُ مُسْلِمُونَ ۝١٣٦
Qoolooo aamannaa billaahi wa maaa unzila ilainaa wa maaa unzila ilaaa Ibraaheema wa Ismaa`eela wa Ishaaqa wa Ya`qooba wal Asbaati wa maaootiya Moosa wa `Eesaa wa maaa ootiyan Nabiyyoona mir Rabbihim laa nufaariq baina ahadim minhum wa nahnu lahoo muslimoon
📖 Ni Yorùbá
E so pe: “A gbagbo ninu Allahu ati ohun ti Won sokale fun wa ati ohun ti Won sokale fun (awon Anabi) ’Ibrohim, ’Ismo‘il, ’Ishaƙ, Ya‘ƙub ati awon aromodomo Ya‘ƙub. (A gbagbo ninu) ohun ti Won fun (awon Anabi) Musa ati ‘Isa, ati ohun ti Won fun awon Anabi (yooku) lati odo Oluwa won. A ko ya eni kan soto ninu won. Awa si ni musulumi (olujuwo-juse sile) fun Un.”

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 134-138 — Surah Al-Baqarah

134تِلْكَ أُمَّةٌ قَدْ خَلَتْ ۖ لَهَا مَا كَسَبَتْ وَلَكُم مَّا كَسَبْتُمْ ۖ وَلَا تُسْأَلُونَ عَمَّا كَانُوا يَعْمَلُونَ
Ijo kan niyen ti o ti lo. Tiwon ni ohun ti won se nise. Tiyin ni ohun ti e se nise. Won ko si nii bi yin leere nipa ohun ti won n se nise
135وَقَالُوا كُونُوا هُودًا أَوْ نَصَارَىٰ تَهْتَدُوا ۗ قُلْ بَلْ مِلَّةَ إِبْرَاهِيمَ حَنِيفًا ۖ وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
Won wi pe: “E je yehudi tabi nasara ki e mona.” So pe: "Rara, esin (Anabi) ’Ibrohim (lesin), oluduro-deede, ko si si ninu awon osebo
136قُولُوا آمَنَّا بِاللَّهِ وَمَا أُنزِلَ إِلَيْنَا وَمَا أُنزِلَ إِلَىٰ إِبْرَاهِيمَ وَإِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ وَيَعْقُوبَ وَالْأَسْبَاطِ وَمَا أُوتِيَ مُوسَىٰ وَعِيسَىٰ وَمَا أُوتِيَ النَّبِيُّونَ مِن رَّبِّهِمْ لَا نُفَرِّقُ بَيْنَ أَحَدٍ مِّنْهُمْ وَنَحْنُ لَهُ مُسْلِمُونَ
E so pe: “A gbagbo ninu Allahu ati ohun ti Won sokale fun wa ati ohun ti Won sokale fun (awon Anabi) ’Ibrohim, ’Ismo‘il, ’Ishaƙ, Ya‘ƙub ati awon aromodomo Ya‘ƙub. (A gbagbo ninu) ohun ti Won fun (awon Anabi) Musa ati ‘Isa, ati ohun ti Won fun awon Anabi (yooku) lati odo Oluwa won. A ko ya eni kan soto ninu won. Awa si ni musulumi (olujuwo-juse sile) fun Un.”
137فَإِنْ آمَنُوا بِمِثْلِ مَا آمَنتُم بِهِ فَقَدِ اهْتَدَوا ۖ وَّإِن تَوَلَّوْا فَإِنَّمَا هُمْ فِي شِقَاقٍ ۖ فَسَيَكْفِيكَهُمُ اللَّهُ ۚ وَهُوَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
Nitori naa, ti won ba gbagbo ninu iru ohun ti e gbagbo, won ti mona. Ti won ba si gbunri, won ti wa ninu iyapa (ododo). Allahu si maa to o (nibi aburu) won. Oun ni Olugbo, Onimo
138صِبْغَةَ اللَّهِ ۖ وَمَنْ أَحْسَنُ مِنَ اللَّهِ صِبْغَةً ۖ وَنَحْنُ لَهُ عَابِدُونَ
(E duro ti) aro Allahu. Ta si l’o dara ju Allahu lo ni aro! Awa si ni olujosin fun Un
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
136Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 136

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 136 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : E so pe: “A gbagbo ninu Allahu ati ohun ti…

Surah Ẹsẹ 136/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 134–138. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers