Al-Baqarah · 138/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Baqarah
صِبْغَةَ اللَّهِ ۖ وَمَنْ أَحْسَنُ مِنَ اللَّهِ صِبْغَةً ۖ وَنَحْنُ لَهُ عَابِدُونَ ١٣٨
Transliteration
Sibghatal laahi wa man ahsanu minal laahi sibghatanw wa nahnu lahoo `aabidoon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
(E duro ti) aro Allahu. Ta si l’o dara ju Allahu lo ni aro! Awa si ni olujosin fun Un
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 136-140 — Al-Baqarah
136قُولُوا آمَنَّا بِاللَّهِ وَمَا أُنزِلَ إِلَيْنَا وَمَا أُنزِلَ إِلَىٰ إِبْرَاهِيمَ وَإِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ وَيَعْقُوبَ وَالْأَسْبَاطِ وَمَا أُوتِيَ مُوسَىٰ وَعِيسَىٰ وَمَا أُوتِيَ النَّبِيُّونَ مِن رَّبِّهِمْ لَا نُفَرِّقُ بَيْنَ أَحَدٍ مِّنْهُمْ وَنَحْنُ لَهُ مُسْلِمُونَ
E so pe: “A gbagbo ninu Allahu ati ohun ti Won sokale fun wa ati ohun ti Won sokale fun (awon Anabi) ’Ibrohim, ’Ismo‘il, ’Ishaƙ, Ya‘ƙub ati awon aromodomo Ya‘ƙub. (A gbagbo ninu) ohun ti Won fun (awon Anabi) Musa ati ‘Isa, ati ohun ti Won fun awon Anabi (yooku) lati odo Oluwa won. A ko ya eni kan soto ninu won. Awa si ni musulumi (olujuwo-juse sile) fun Un.”
137فَإِنْ آمَنُوا بِمِثْلِ مَا آمَنتُم بِهِ فَقَدِ اهْتَدَوا ۖ وَّإِن تَوَلَّوْا فَإِنَّمَا هُمْ فِي شِقَاقٍ ۖ فَسَيَكْفِيكَهُمُ اللَّهُ ۚ وَهُوَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
Nitori naa, ti won ba gbagbo ninu iru ohun ti e gbagbo, won ti mona. Ti won ba si gbunri, won ti wa ninu iyapa (ododo). Allahu si maa to o (nibi aburu) won. Oun ni Olugbo, Onimo
138صِبْغَةَ اللَّهِ ۖ وَمَنْ أَحْسَنُ مِنَ اللَّهِ صِبْغَةً ۖ وَنَحْنُ لَهُ عَابِدُونَ
(E duro ti) aro Allahu. Ta si l’o dara ju Allahu lo ni aro! Awa si ni olujosin fun Un
139قُلْ أَتُحَاجُّونَنَا فِي اللَّهِ وَهُوَ رَبُّنَا وَرَبُّكُمْ وَلَنَا أَعْمَالُنَا وَلَكُمْ أَعْمَالُكُمْ وَنَحْنُ لَهُ مُخْلِصُونَ
So pe: “Se eyin yo ja wa niyan nipa Allahu ni?” Oun si ni Oluwa wa ati Oluwa yin. Tiwa ni awon ise wa. Tiyin si ni awon ise yin. Awa (musulumi) si ni olusafomo-esin fun Un
140أَمْ تَقُولُونَ إِنَّ إِبْرَاهِيمَ وَإِسْمَاعِيلَ وَإِسْحَاقَ وَيَعْقُوبَ وَالْأَسْبَاطَ كَانُوا هُودًا أَوْ نَصَارَىٰ ۗ قُلْ أَأَنتُمْ أَعْلَمُ أَمِ اللَّهُ ۗ وَمَنْ أَظْلَمُ مِمَّن كَتَمَ شَهَادَةً عِندَهُ مِنَ اللَّهِ ۗ وَمَا اللَّهُ بِغَافِلٍ عَمَّا تَعْمَلُونَ
Tabi e n wi pe: “Dajudaju (awon Anabi) ’Ibrohim, ’Ismo‘il, ’Ishaƙ, Ya‘ƙub ati awon aromodomo Ya‘ƙub, won je yehudi tabi nasara.” So pe: “Se eyin l’e nimo julo (nipa won ni) tabi Allahu?” Ta l’o sabosi ju eni t’o daso bo eri odo re (ti o sokale) lati odo Allahu? Allahu ko si nii gbagbe ohun ti e n se nise
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
138Ẹsẹ
Itumọ — Al-Baqarah 138
Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 138 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (E duro ti) aro Allahu. Ta si l’o dara ju…Surah Ẹsẹ 138/286 — Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Baqarah Gbọ, Al-Baqarah Itumọ, Al-Baqarah mp3, Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 136–140. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








