Al-Baqarah · 244/286
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Baqarah
وَقَاتِلُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ سَمِيعٌ عَلِيمٌ ۝٢٤٤
Wa qaatiloo fee sabeelil laahi wa`lamooo annal laaha Samee`un `Aleem
📖 Ni Yorùbá
E jagun fun aabo esin Allahu, ki e si mo pe dajudaju Allahu ni Olugbo, Onimo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 242-246 — Surah Al-Baqarah

242كَذَٰلِكَ يُبَيِّنُ اللَّهُ لَكُمْ آيَاتِهِ لَعَلَّكُمْ تَعْقِلُونَ
Bayen ni Allahu se n salaye awon ayah Re fun yin, nitori ki e le se laakaye
243۞ أَلَمْ تَرَ إِلَى الَّذِينَ خَرَجُوا مِن دِيَارِهِمْ وَهُمْ أُلُوفٌ حَذَرَ الْمَوْتِ فَقَالَ لَهُمُ اللَّهُ مُوتُوا ثُمَّ أَحْيَاهُمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَذُو فَضْلٍ عَلَى النَّاسِ وَلَٰكِنَّ أَكْثَرَ النَّاسِ لَا يَشْكُرُونَ
Se o o ri awon t’o jade lati inu ile won legbeegberun nitori iberu iku! Allahu si so fun won pe: “E ku.” Leyin naa, O so won di alaaye. Dajudaju Allahu ni Oloore-ajulo lori awon eniyan, sugbon opolopo eniyan ko dupe (fun Un)
244وَقَاتِلُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ سَمِيعٌ عَلِيمٌ
E jagun fun aabo esin Allahu, ki e si mo pe dajudaju Allahu ni Olugbo, Onimo
245مَّن ذَا الَّذِي يُقْرِضُ اللَّهَ قَرْضًا حَسَنًا فَيُضَاعِفَهُ لَهُ أَضْعَافًا كَثِيرَةً ۚ وَاللَّهُ يَقْبِضُ وَيَبْسُطُ وَإِلَيْهِ تُرْجَعُونَ
Ta ni eni ti o maa ya Allahu ni dukia t’o dara, ki Allahu si se adipele (esan) fun un ni adipele pupo? Allahu n ka oro nile, O si n te e sile. Odo Re si ni won yoo da yin pada si
246أَلَمْ تَرَ إِلَى الْمَلَإِ مِن بَنِي إِسْرَائِيلَ مِن بَعْدِ مُوسَىٰ إِذْ قَالُوا لِنَبِيٍّ لَّهُمُ ابْعَثْ لَنَا مَلِكًا نُّقَاتِلْ فِي سَبِيلِ اللَّهِ ۖ قَالَ هَلْ عَسَيْتُمْ إِن كُتِبَ عَلَيْكُمُ الْقِتَالُ أَلَّا تُقَاتِلُوا ۖ قَالُوا وَمَا لَنَا أَلَّا نُقَاتِلَ فِي سَبِيلِ اللَّهِ وَقَدْ أُخْرِجْنَا مِن دِيَارِنَا وَأَبْنَائِنَا ۖ فَلَمَّا كُتِبَ عَلَيْهِمُ الْقِتَالُ تَوَلَّوْا إِلَّا قَلِيلًا مِّنْهُمْ ۗ وَاللَّهُ عَلِيمٌ بِالظَّالِمِينَ
Se o o ri awon asiwaju ninu awon omo ’Isro’il, leyin (igba Anabi) Musa? Nigba ti won wi fun Anabi tiwon pe: “Yan oba kan fun wa, ki a lo jagun fun aabo esin Allahu.” O so pe: “Sebi o se e se pe ti Won ba se ogun jija ni oran-anyan le yin lori tan e o kuku nii jagun?” Won wi pe: "Ki ni o maa di wa lowo lati jagun fun aabo esin Allahu? Won kuku ti le awa ati awon omo wa jade kuro ninu ile wa!" Amo nigba ti A se ogun esin ni oran-anyan le won lori tan, won peyin da afi die ninu won. Allahu si ni Onimo nipa awon alabosi
Al-BaqarahAtokọ Kurani
286Ẹsẹ
MedinanRevelation
244Ẹsẹ

Itumọ — Al-Baqarah 244

Surah Al-Baqarah Ẹsẹ 244 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : E jagun fun aabo esin Allahu, ki e si mo…

Surah Ẹsẹ 244/286 — Surah Al-Baqarah البقرة (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Baqarah Gbọ, Surah Al-Baqarah Itumọ, Surah Al-Baqarah mp3, Surah Al-Baqarah pdf. Ẹsẹ 242–246. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers