Al-Anbiya · 36/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Anbiya
وَإِذَا رَآكَ الَّذِينَ كَفَرُوا إِن يَتَّخِذُونَكَ إِلَّا هُزُوًا أَهَٰذَا الَّذِي يَذْكُرُ آلِهَتَكُمْ وَهُم بِذِكْرِ الرَّحْمَٰنِ هُمْ كَافِرُونَ ۝٣٦
Wa izaa ra aakal lazeena kafarooo iny-yattakhizoonaka illa huzuwaa; ahaazal lazee yazkuru aalihatakum wa hum bi zikrir Rahmaani hum kaafiroon
📖 Ni Yorùbá
Nigba ti awon t’o sai gbagbo ba ri o, won ko si nii ka o kun kini kan bi ko se oniyeye pe: “Se eyi ni eni t’o n soro nipa awon olohun yin?” Alaigbagbo si ni awon naa nipa iranti Ajoke-aye

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 34-38 — Surah Al-Anbiya

34وَمَا جَعَلْنَا لِبَشَرٍ مِّن قَبْلِكَ الْخُلْدَ ۖ أَفَإِن مِّتَّ فَهُمُ الْخَالِدُونَ
A ko se bibe gbere fun abara kan siwaju re. Nje ti o ba ku, awon si ni olusegbere bi
35كُلُّ نَفْسٍ ذَائِقَةُ الْمَوْتِ ۗ وَنَبْلُوكُم بِالشَّرِّ وَالْخَيْرِ فِتْنَةً ۖ وَإِلَيْنَا تُرْجَعُونَ
Emi kookan l’o maa to iku wo. A si maa fi aburu ati rere sadanwo fun yin. Odo Wa si ni won yoo da yin pada si
36وَإِذَا رَآكَ الَّذِينَ كَفَرُوا إِن يَتَّخِذُونَكَ إِلَّا هُزُوًا أَهَٰذَا الَّذِي يَذْكُرُ آلِهَتَكُمْ وَهُم بِذِكْرِ الرَّحْمَٰنِ هُمْ كَافِرُونَ
Nigba ti awon t’o sai gbagbo ba ri o, won ko si nii ka o kun kini kan bi ko se oniyeye pe: “Se eyi ni eni t’o n soro nipa awon olohun yin?” Alaigbagbo si ni awon naa nipa iranti Ajoke-aye
37خُلِقَ الْإِنسَانُ مِنْ عَجَلٍ ۚ سَأُرِيكُمْ آيَاتِي فَلَا تَسْتَعْجِلُونِ
Won fi ikanju se eniyan. Mo maa fi awon ami Mi han yin. Nitori naa, e ma se kan Mi loju
38وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا الْوَعْدُ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
Won si n wi pe: “Igba wo ni ileri yii yoo se na, ti e ba je olododo?”
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
36Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 36

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 36 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nigba ti awon t’o sai gbagbo ba ri o, won…

Surah Ẹsẹ 36/112 — Surah Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Anbiya Gbọ, Surah Al-Anbiya Itumọ, Surah Al-Anbiya mp3, Surah Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 34–38. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers