Aal-Imran · 183/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
الَّذِينَ قَالُوا إِنَّ اللَّهَ عَهِدَ إِلَيْنَا أَلَّا نُؤْمِنَ لِرَسُولٍ حَتَّىٰ يَأْتِيَنَا بِقُرْبَانٍ تَأْكُلُهُ النَّارُ ۗ قُلْ قَدْ جَاءَكُمْ رُسُلٌ مِّن قَبْلِي بِالْبَيِّنَاتِ وَبِالَّذِي قُلْتُمْ فَلِمَ قَتَلْتُمُوهُمْ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ ۝١٨٣
Allazeena qaalooo innal laaha `ahida ilainaaa allaa nu`mina liRasoolin hatta yaa tiyanaa biqurbaanin taa kuluhun naar; qul qad jaaa`akum Rusulum min qablee bilbaiyinaati wa billazee qultum falima qataltumoohum in kuntum saadiqeen
📖 Ni Yorùbá
Awon t’o wi pe: "Dajudaju Allahu sadehun fun wa pe a o gbodo gba Ojise kan gbo titi o maa fi mu saraa kan wa fun wa ti ina (atorunwa) yoo fi lanu." So pe: "Dajudaju awon Ojise kan ti wa ba yin siwaju mi pelu awon eri to yanju ati eyi ti e wi (yii), nitori ki ni e fi pa won ti e ba je olododo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 181-185 — Surah Aal-Imran

181لَّقَدْ سَمِعَ اللَّهُ قَوْلَ الَّذِينَ قَالُوا إِنَّ اللَّهَ فَقِيرٌ وَنَحْنُ أَغْنِيَاءُ ۘ سَنَكْتُبُ مَا قَالُوا وَقَتْلَهُمُ الْأَنبِيَاءَ بِغَيْرِ حَقٍّ وَنَقُولُ ذُوقُوا عَذَابَ الْحَرِيقِ
Allahu kuku ti gbo oro awon t’o wi pe: “Dajudaju alaini ni Allahu, awa si ni oloro.” A maa sakosile ohun ti won wi ati pipa ti won pa awon Anabi lai letoo. A si maa so pe: “E to iya Ina jonijoni wo.”
182ذَٰلِكَ بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيكُمْ وَأَنَّ اللَّهَ لَيْسَ بِظَلَّامٍ لِّلْعَبِيدِ
Iyen (ri bee) nitori ohun ti owo yin ti siwaju. Ati pe dajudaju Allahu ko nii se abosi fun awon eru (Re)
183الَّذِينَ قَالُوا إِنَّ اللَّهَ عَهِدَ إِلَيْنَا أَلَّا نُؤْمِنَ لِرَسُولٍ حَتَّىٰ يَأْتِيَنَا بِقُرْبَانٍ تَأْكُلُهُ النَّارُ ۗ قُلْ قَدْ جَاءَكُمْ رُسُلٌ مِّن قَبْلِي بِالْبَيِّنَاتِ وَبِالَّذِي قُلْتُمْ فَلِمَ قَتَلْتُمُوهُمْ إِن كُنتُمْ صَادِقِينَ
Awon t’o wi pe: "Dajudaju Allahu sadehun fun wa pe a o gbodo gba Ojise kan gbo titi o maa fi mu saraa kan wa fun wa ti ina (atorunwa) yoo fi lanu." So pe: "Dajudaju awon Ojise kan ti wa ba yin siwaju mi pelu awon eri to yanju ati eyi ti e wi (yii), nitori ki ni e fi pa won ti e ba je olododo
184فَإِن كَذَّبُوكَ فَقَدْ كُذِّبَ رُسُلٌ مِّن قَبْلِكَ جَاءُوا بِالْبَيِّنَاتِ وَالزُّبُرِ وَالْكِتَابِ الْمُنِيرِ
Ti won ba pe o ni opuro, won kuku ti pe awon Ojise t’o siwaju re ni opuro. Won wa pelu awon eri t’o yanju, ipin-ipin Tira ati Tira t’o n tanmole si oro esin
185كُلُّ نَفْسٍ ذَائِقَةُ الْمَوْتِ ۗ وَإِنَّمَا تُوَفَّوْنَ أُجُورَكُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ ۖ فَمَن زُحْزِحَ عَنِ النَّارِ وَأُدْخِلَ الْجَنَّةَ فَقَدْ فَازَ ۗ وَمَا الْحَيَاةُ الدُّنْيَا إِلَّا مَتَاعُ الْغُرُورِ
Emi kookan lo maa to iku wo. A o si san yin ni esan yin ni ekunrere ni Ojo Ajinde. Nitori naa, enikeni ti A ba mu jinna tefe si Ina, ti A si mu wo inu Ogba Idera, o kuku ti jere. Ki si ni igbesi aye bi ko se igbadun etan
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
183Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 183

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 183 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon t’o wi pe: "Dajudaju Allahu sadehun fun wa pe…

Surah Ẹsẹ 183/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 181–185. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers