Sad · 62/88
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Sad
وَقَالُوا مَا لَنَا لَا نَرَىٰ رِجَالًا كُنَّا نَعُدُّهُم مِّنَ الْأَشْرَارِ ۝٦٢
Wa qaaloo ma lanaa laa naraa rijaalan kunnaa na`udduhum minal ashraar
📖 Ni Yorùbá
Won tun wi pe: "Ki lo sele si wa ti a o ri awon okunrin kan, awon ti a n ka mo awon eni buruku

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 60-64 — Surah Sad

60قَالُوا بَلْ أَنتُمْ لَا مَرْحَبًا بِكُمْ ۖ أَنتُمْ قَدَّمْتُمُوهُ لَنَا ۖ فَبِئْسَ الْقَرَارُ
(Awon omoleyin ninu Ina) maa wi pe: "Rara, eyin naa ko si maawole-maarora fun yin. Eyin l’e pe wa sibi eyi (t’o bi Ina)." O si buru ni ibugbe
61قَالُوا رَبَّنَا مَن قَدَّمَ لَنَا هَٰذَا فَزِدْهُ عَذَابًا ضِعْفًا فِي النَّارِ
Won (tun) wi pe: "Oluwa wa, eni ti o pe wa (sibi iya) yii, se alekun adipele iya fun un ninu Ina
62وَقَالُوا مَا لَنَا لَا نَرَىٰ رِجَالًا كُنَّا نَعُدُّهُم مِّنَ الْأَشْرَارِ
Won tun wi pe: "Ki lo sele si wa ti a o ri awon okunrin kan, awon ti a n ka mo awon eni buruku
63أَتَّخَذْنَاهُمْ سِخْرِيًّا أَمْ زَاغَتْ عَنْهُمُ الْأَبْصَارُ
Sebi a fi won se yeye tabi awon oju ti fo won ni (l’a o fi ri won ninu Ina)
64إِنَّ ذَٰلِكَ لَحَقٌّ تَخَاصُمُ أَهْلِ النَّارِ
Dajudaju iyen, ariyanjiyan awon ero inu Ina, ododo ma ni
SadAtokọ Kurani
88Ẹsẹ
MeccanRevelation
62Ẹsẹ

Itumọ — Sad 62

Surah Sad Ẹsẹ 62 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won tun wi pe: "Ki lo sele si wa ti…

Surah Ẹsẹ 62/88 — Surah Sad ص (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Sad Gbọ, Surah Sad Itumọ, Surah Sad mp3, Surah Sad pdf. Ẹsẹ 60–64. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers